YORUBA PRIMARY 5

Second Term Examination Questions Yoruba Primary 5 Second Term

SECOND TERM EXAMINATION  CLASS: PRIMARY 5 SUBJECT: YORUBA NAME: ___________________________________________ I. Ko orin ibile kan fun ayeye, eyikeyi ti o ba mo, o le je nibi igbeyawo, nibi isomo loruko tabi nibi oye jije. Daruko igbese marun-un ninu asa igbeyawo abinibi ki o se alaye okan ninu won. II. IWE KIKA DAROSA Kini so darosa