Isori oro +ninu gbolohun

OSE KOKANLA

EKA ISE: EDE

AKOLE ISE: ISORI ORO NINU GBOLOHUN

Isori oro ni abala ti a pin awon oro inu ede yoruba si.

 

Isori oro Yoruba

  1. oro-oruko (NOUN)
  2. oro-aropo oruko (PRONOUN)
  3. oro ise (VERB)
  4. oro Aropo afarajoruko (PROMINAL )
  5. oro apejuwe ( ADJECTIVE )
  6. oro atoku (PREPOSITION)
  7. oro asopo ( CONJUCTION )

EKA ISE: ASA

AKOLE ISE: ISINKU

Isinku ni eye ikeyin ti a se fun oku logan ti o ku titi di akoko ti a fi sin.

Orisi oku sinsin ni ile Yoruba

  1. Oku Oba
  2. Oku Ijoye
  3. Oku Alaboyun
  4. Oku Adete
  5. Oku Abuke
  6. Oku Afin
  7. Oku Odo
  8. Oku Aro
  9. Oku eni ti o pokunso
  10. Oku eni ti sango pa
  11. Oku eni ti igi yalu pa abbl.

Ohun elo oku sin-sin.

a. Aso funfun

b. poosi oku/eni

d. etutu lorisirisi

e. owu tutu

e. igi ora

f. eepe (iyepe)

g. lofinde oloorun

gb. Oniruuru nnkan ti enu n je, ileke owo, bata, opa itile abbl.

Igbelewon:

  • Fun asa isinku ni oriki
  • Ko orisi oku sin sin ni ile Yoruba mewaa
  • Ko ohun elo oku sin sin nile Yoruba
  • Ko isori oro ede Yoruba mefa

Ise asetilewa: fun awon isori oro wonyi loriki pelu apeere meji meji:

  1. Oro oruko
  2. Oro ise
Spread the word if you find this helpful! Click on any social media icon to share