Yoruba

YORUBA LANGUAGE PRIMARY 5 FIRST TERM EXAMINATION 

FIRST TERM EXAMINATION  CLASS: PRIMARY 5 SUBJECT: YORUBA LANGUAGE NAME:…………………………………………………………………………………… Ere Idaraya: – Ere Ayo ________ ni igi gborogidi ti a gbe iho mejila si (a) opon ayo (b) odo _________ ni omo ayo (a) ileke (b) eso igi Omo ayo _________ ni o ngbe ni oju opon (a) merinlelogun (b) mejidinladota Apa __________ ni

YORUBA LANGUAGE PRIMARY 4 FIRST TERM EXAMINATION 

FIRST TERM EXAMINATION  CLASS: PRIMARY 4 SUBJECT: YORUBA LANGUAGE NAME:…………………………………………………………………………………… Iwe Kika: – Asinnu Ole __________ ni oruko oja ilu pokii (a) ikilo (b) ayelu Ohun ti o se akoba fun pokii nip e (a) o nra epa je (b) o ni ore pupo __________ ni o bu pokii pe: Lanboroki, oju re jaa (a)

YORUBA LANGUAGE PRIMARY 3 FIRST TERM EXAMINATION

FIRST TERM EXAMINATION  CLASS: PRIMARY 3 SUBJECT: YORUBA LANGUAGE NAME:…………………………………………………………………………………… Ewi: Ibawi E dake je je je Omo ile-eko, e gbohun enu mi Eje nkorin ara si yin leti Bee room ile-eko To nsojika Arofo yii nba omo ______ wi (a) omo ile-eko (b) omo ile-ise ______ to gbobawi ni dee ni _____ leyin ola

YORUBA LANGUAGE PRIMARY 1 FIRST TERM EXAMINATION 

FIRST TERM EXAMINATION  CLASS: PRIMARY 1 SUBJECT: YORUBA LANGUAGE NAME:…………………………………………………………………………………… Iro Ede: Di alafo awon leta wonyii A ______ d ______ e ______ g ______ h ______ j ______ l ______ n ______ o ______ r _______ s Kini Oruko awon aworan wonyii (Lodo, opon) (ibon, igi) (irin, okun) (ayan, eye) (igba, irin) Di awon

Yoruba BASIC 2 1st TERM EXAMINATION Primary 2

  1st TERM EXAMINATION CLASS: BASIC 2 SUBJECT: Yoruba Pin awon oro wonyi si silebu 1. Eleran 2. adesola 3. Omode 4. Koroba 5. Silebu AKAYE Jide je omo onipanle ati alaigboran.Kii f’eti sile si ohun ti awon obi re ba n so. Opo igba ni yio kuro nile ti ko si ni lo si

Akole:onka ni ede Yoruba lati ori ookan de ogun 

Pry one Ose kefa Akole:onka ni ede Yoruba lati ori ookan de ogun 1-Ookan 2-Eeji 3-Eeta 4-Eerin 5-Aarun 6-Eefa 7-Eeje 8-Eejo 9-Eesan 10-Ewaa 11-Okanla 12-Ejila 13-Etala 14-Erinla 15-Aarundinlogun 16-Eerindinlogun 17-Eetadinlogun 18-Ejidinlogun 19-Okandinlogun 20-ogun-un   Ise kilaasi   Kinni oruko awon nomba yii ni ede yoruba   1.11(a)etala (b)okanla   2.13(a)okanla (b)etala   3.15 (a)arundinlogun (b)arundinlogbon

Ere Okoto títa ni ile Yoruba

  Class: Pry one Akole:Ere idaraya ni ile yoruba (ere okoto) Eniyan meji tabi meta le ta okoto lekan naa. Ori ile didan ni a ti maa nta okota. Paanu ti a ka,ti idi re ri soso ni a fi nse okoto. Okoto maa nj roinroin ti a ba nta. Ti aba ta okoto ti

A—Aaja. Yorùbá

Class: Pry one Subject: Yoruba Studies Akole:lilo leta ede yoruba loro A—Aaja B—Bata D—Doje E—Ejo E—-Eye F—-Fila G—-Gele Gb—-Gbaguda H—-Hausa I—-Igi J—-Jagunjagun K—Kiniun L—–Labalaba M—–Maalu N—–Nahudu O—-Ogongo O—-Ogede P—-Pepeye R—-Rakunmi S—-salubata S—-sango T—-Tafatafa U—-Uku UK u W—-Waala Y—-Yanmuyanmu Ise kilaasi A duro fun ___ (a) aja. (b)ologbo B duro fun kinni ____ (a) apo (b)

ÀWỌN FAWELI ATI KONSONANTI EDE YORUBA 

Àwọn Faweeli àti konsananti tí ó wà nínú Èdè Yorùbá Class: Pry one Subject: Yoruba Studies Akole: FAWELI ATI KONSONANTI EDE YORUBA   Faweli yoruba pin si ona meji awon naa nii 1 Airanmupe 2 Aranmupe   1 FAWELI AIRANMUPE: A E E I O O U   2 FAWELI ARANMUPE: AN EN IN ON