YORUBA LANGUAGE PRIMARY 3 FIRST TERM EXAMINATION

FIRST TERM EXAMINATION 

CLASS: PRIMARY 3 SUBJECT: YORUBA LANGUAGE

NAME:……………………………………………………………………………………

  1. Ewi: Ibawi

E dake je je je

Omo ile-eko, e gbohun enu mi

Eje nkorin ara si yin leti

Bee room ile-eko

To nsojika

  1. Arofo yii nba omo ______ wi (a) omo ile-eko (b) omo ile-ise
  2. ______ to gbobawi ni dee ni _____ leyin ola (a) Agba buruku (b) Omo giga
  3. Omo to gbo _____ nii fi ______ sese rin (a) ija, igi (b) ibawi, mo to
  4. Eko ndi ________ fomo to gbo ibawi (a) iya (b) deko
  5. Eyin ______ e gboro _________ yewo (a) Omode, agba (b) gende, ikoko
  6. Huwa Imoore Si Obi Re: Ewi

Adandori kodo

O nwose eye

Eje ka ronu wo

Ka mob aye ti nto

Ka mohun ti nsele nile, loko ati nibi gbogbo

Baba rook olowo

Nitori ati tomo

Idahun

  1. _________ dori kodo (a) Adan (b) Igun
  2. O nwose ______________ (a) Eran (b) Eye
  3. E toju awon _________ (a) odo (b) obi
  4. Eyin _________ gbogbo (a) Agba (b) Omode
  5. __________ yii ko to rara (a) Iwa (b) Ogbon
  6. Itoju Ara
  7. Ojoojumo ni ________ nfo eyin re (a) Bola (b) Ade
  8. A we gbogbo ________ re da saka (a) Ara (b) Inu
  9. Nitori _________ ara (a) Egbo (b) Eeri
  10. _________ re a mo nini ni gbogbo igba (a) Aso (b) bata
  11. Year funwa ________ patapata (a) Ika (b) Obun
  12. Itoju Ile
  13. Itoju ___________ se Pataki ara (a) Ile (b) Omi
  14. Bi ayika ile doti __________ nii fa (a) Oorun (b) Aisan
  15. Ayika mimo a maa seni ni ________ (a) loge (b) lomo
  16. Ka maa gbegbein laaye rara, nitori ______ arun (a) itankale (b) iseniloore
  17. ________ o yemo eniyan (a) iya (b) obun