THIRD TERM EXAMINATION FOR PRIMARY SCHOOLS PRIMARY 1 TO PRIMARY 6 YORUBA
THIRD TERM
SUBJECT: YORUBA CLASS: KILAASI KINNI
Dahun gbogbo awon ibeere wonyi
- Ori ibo ni a maa n sun si? (a) ori odo (b) ori sitoofu (d) ori beedi
- Bi mo ba kawe mi ____ mi a dun koko ka (a) bata (b) iwe (d) obe
- Apeere nnkan sise ni _____ (a) igi (b) dobale (d) aga
- ____ ni o le segun arun gbogbo (a) imototo (b) beedi (d) rula
- Nje o dara ki a maa a ja? (a) o dara (b) ko dara (d) n ko mo
- Kini 11 ni onka Yoruba? (a) Eejila (b) Eefa (d) ookanla
- Kini Aiku ni ede geesi? (a) Sunday (b) Tuesday (c) Friday
- Obinrin maa n ___irun won (a) di (b) jo (d) sa
- okunrin maa n ____irun won (a) se (b) ge (d) pin
- Bawo ni a se n ki eniyan ni osan? (a) e kale (b) e kuurole (d) e kaasan
Kini oruko awon aworan wonyii:-
- 12.
(a) obe (b) agogo (d) iwe
- 14.
(a) tabili (b) aso (d) sibi
IPIN KEJI: Dahun awon ibeere wonyi . Ko leta alifabeeti lati ori A-S
a, ________, d , _______, e, _________, g, ________, h, ________,j, __________, i,_______, n, ______, o, _________, r.
so onka wonyi papo pelu nomba ti o ye.
[mediator_tech]
THIRD TERM
SUBJECT: YORUBA CLASS: KILAASI KEJI
Dahun gbogbo awon ibeere wonyi
- Bawo ni a se n ki eniyan ni akoko oye (a) e ku idaraya (b) E ku otutu (d) E ku odun
- _____ ni ege oro ti o lee ba eemi jade leekan soso (a) silebu (b) tabili (d) Aga
- Kini o maa n sele ni igba ooru? (a) otutu maa n mu (b) ata maa n po (d) ooru maa n mu
- ____ ti ko ni iru olorun lon ba a le esinsin (a) Aja (b) maluu (d) Elede
- Kini o lee segun arun gbogbo (a) olopaa (b) imototo (d) akekoo
- Leta wo ni o gbeyin ninu leta alifabeeti Yoruba (A) leta B (b) leta D (d) Leta Y
- Silebu meloo ni o wa ninu baba (a) silebu kan (b) silebu meta (d) silebu meji
- A maa n sun si ori ____(a) firigi (b) beedi (d) sitoofu
- Ohun elo ti a fi n gbale ni (a) igbale (b) ose (d) agolo
- N je o dara ki a maa so otito (a) beeni (b) beeko (d) n ko mo
- ______ funfun ko mo ara re lagba (a) adiye (b) opolo (d) agutan
- Bawo ni a se n ki eniyan ni ale (a) e kaaro (b) e kaasan (d) e kale
- ____ n lota ileke n saso (a) baba (b) iyawo (d) omode
- ____ je okan ninu ohun elo ile (a) telifisan (b) igi (d) reluwe
- Apeere sise nnkan ni ____(a) gbale (b) sitoofu (d) taya
Ninu itan ijapa ati igbin ti a ka
- Tani o lo mu erin wa lati inu igbo? (a) Ijapa (b) obo (d) elede
- Kini ijapa so fun erin pe won fe se fun (a) won fe na (b) won fe fi je oba (d) won fe fun lowo
- kini Ijapa fun erin je? (a) dodo (b) akara oloyin (d) eja dindin
- Kini awon ara ilu se fun erin? (a) won na (b) won gbe (d) won pa
- Nje o dara ki a maa se oju kokoro? (a) o dara (b) N ko mo (d) ko dara
IPIN KEJI
(A). Dahun gbogbo awon ibeere wonyi
Ko leta alifabeeti Yoruba jade
A ___ ___ ___ ___ ___ ___ ___ ___ ___ ___ ___ ___ ___ ___ ___ ___ ___ ___ ___ ___ ___ ___ ___ ___
(B). Pin awon oro wonyi si silebu.
(1) Ada- ____________________
(2) Obe- ____________________
(3) Baba- ______________________
(4) Iya- ________________________
(5) ese- ________________________
(6) Ata- ________________________
(7) Bola – _______________________
(8) dodo – ___________________________
[mediator_tech]
THIRD TERM
SUBJECT: YORUBA CLASS: KILAASI KETA
Dahun gbogbo awon ibeere wonyi
- Apa ibo ni a ti gbodo maa rin ti a ba n rin ni opopona oko (a) apa osi (b) apa otun (d) nko mo
- Nje o dara ki a maa hu iwa rere (a) o dara (b) ko dara (d) n ko mo
- Awo dudun ni a n pe ni ___ni ede geesi (a) red (b) blue (d) black
- Kini o le segun arun gbogbo (a) owo (b) oba (d) imototo
- Kini a fi n gbale? (a) sibi (b) igbale (d) obe
- Kini ohun akoko ti a gbodo se ti a ba fe jeun? (a) sare (b) fo owo wa (d) fo ese wa
- Apeere ise owo ni ile Yoruba ni ___(a) ise alagbede (b) ise osu (d) ise panapana
- Kini o koja niwaju ile oba ti ko ki oba? (a) maluu (b) esinsin (d) ejo
- Kini Eetalelaadota ni nomba (a) 35 (b) 53 (d) 76
- Kini nomba yii 50 ni onka Yoruba (a) ogbon (b) ogun (d) Aadota
- Silebu meloo ni o wa ninu Ade? (a) mewa (b) merin (d) meji
Ninu itan ijapa : idi ti imu ijapa fi ku kanbo
- Kini oruko awon ore ninu itan yii? (a) ijapa ati okere (b) ijapa ati aja (d) aja ati okere
- Awon wo ni o n ja? (a) asin ati okere (b) Ijapa ati asin (d) oba ati aja
- Tani o ge imu ijapa je? (a) asin (b) okere (d) ekute
- Tani o n korin ninu itan yi (a) okere (b) asin (d) ijapa
- Oruko akoni ile yoruba ti a menuba ni ____(a) Oduduwa (b) Awolowo (d) tinubu
- Nje o dara ki a maa jale (a) ko dara (b) o dara (d) N ko mo
- Yara idana ni a n pe ni ____(a) bathroom (b) kitchen (d) toilet
- Ojuse obi si omo ni ___(a) sisan owo ile iwe (b) fifi omo se erun (d) fifi omo dogo
- Ohun elo fun ise agbe ni ___(a) ibon (b) ada (d) ofa
IPIN KEJI: Dahun gbogbo awon ibeere wonyi
- Ko oruko awon awo wonyi nine de geesi
- Awo pupa – _____________________ (2) Awo olomi aro – _____________________
iii.Awo dudu – ______________________ (iv) Awo funfun – ______________________
- Awo eweko – _____________________
- Ko awon onka wonyi ni nomba
- Eejilelogoji – _____________________ ii. Eejilelaadota – _________________________
iii. Aarundinlogota – ___________________ iv. Ogota – ____________________________
- Aadota – _________________________
- Apeko
- ____________________________________ ii. _______________________________
iii. ____________________________________ iv. _______________________________
- ____________________________________ vi. _______________________________
vii. ____________________________________ viii. _______________________________
- ____________________________________ x. _______________________________
THIRD TERM
SUBJECT: YORUBA CLASS: KILAASI KERIN
Dahun gbogbo awon ibeere wonyi
- Oriki orile yato si oriki ilu (a) beeko (b) beeni (d) n ko mo
- Kini ogota ni nomba (a) 50 (b) 70 (d) 60
- Okan lara awon ohun ti o maa n han ninu oriki ilu ni ___(a) orisa ilu (b) awo (d) ilu
- Apeere oro oruko aseeka ni ___(a) aga (b) oyin (d) omi
- Omo olofa mojo , olalomi omo abisu joruko awon iran wo ni a n ki bayi? (a) oluoje (b) olofa (d) opomulero
- Kemi sun fonfon, kini oro oruko ninu gbolohun naa? (a) sun (b) fonfon (d) kemi
- Okan lara apeere aroko ni ___(a) aroko alapejuwe (b) aroko onikalamu (d) aroko Oba
- Ijamba moto to soju mi je aroko ___(a) aroko onileta (b) aroko oniroyin (d) aroko ajiroro
- Ohun ti ko dara ti a ko gbodo se ni a n pe ni ___(a) eewo (b) ere ayo tita (d) ere owo
- Tani o fi omo re rubo fun odo Esinmiri? (a) Moremi (b) Tinubu (d) Ajayi Crowther
- Odun wo ni a bi Obafemi Awolowo (a) 1909 (b) 1910 (d) 1991
- Tani o se atunko bibeli lati ede geesi si ede Yoruba (a) moremi (b) Ajayi Crowther (d) Mosudi
- Tani obinrin akoko ti o koko wa oko mi orile ede Naijiria (a) olufunmilayo Kuti (b) Moremi (d) Efunroye
- Ilu ibo ni efunroye Tinubu pada si, leyin ti o kuro ni ilu Eko (a) Ijebu (b) Abeokuta /Egba (d) Ijanikin
- Meloo ni ami ohun ti o wa (a) meje (b) mejila (d) meta
- Ilu ti o wa fun gbogbo ayeye ni (a) dundun (b) agere (d) seli
- Kini Aadorin ni nomba? (a) 80 (b) 90 (d) 70
- Kini a n pe Ojo Abameta ni ede geesi? (a) Tuesday (b) Saturday (d) Monday
- Owara ni a pe ni ____ni ede geesi (a) November (b) January (d) October
- Idakeji olowo ni ____(a) olode (b) Talaka (d) amugo
- Itumo ile eko aladaani ni ile eko____ (a) olowo (b) nla (d) ti ki I se ijoba lo ni
Ninu iwe kika Ajoke se bebe
- Agogo meloo ni alaga ojo naa de? (a) mesan-an (b) mewaa ku iseju mewaa
(d) mewaa ku iseju marun
- Meloo ni awon akekoo ti n jade lo (a) ogorun (b) aadota (d) ogoji
- Apapo ebun ti Ajoke Akanji gba ni ojo naa ko din ni ____ (a)mewa (b) mejo (d) mejila
- Kini Ajoke se, ti won fi so pe o se bebe? (a) Ajoke ni o gba ebun ti o po ju
(b) Ajoke sun (d)Ajoke salo
NInu itan aworawo ko kan tise
- Asiko wo ni aworawo maa n de oko olowo re (a) owuro (b) osan (d) irole
- Kin o sele lojo kan ti o n ko ebe? (a) o ri oru owo (b) o ri kinun (d) o ri ejo
- Owo ti aworawo ri to elo (a) ogofa naira (b) ogoji naira (d) ogorun naira
- Kin ni Aworawo se si owo owo naa? (a) o gbe salo (b) ko fowo kan (d) o gbe owo naa lo fun ola ti I se olowo re
- Kin ni o sele si Aworawo ni igbeyin? (a) o ku (b) o di oba (d) o di ole
IPIN KEJI : Dahun gbogbo awon ibeere wonyi:
- Ko awon onka wonyi ni nomba
- Eetalelogota = _______________________
- Aadorin= __________________
iii. Ookanlelaadota = ___________________________
- Aarundinlogota = _______________________
v Aadota = _______________________________
- Daruko akoni ile Yoruba marun
- ________________________________ ii. ________________________
iii. _______________________________ iv. ________________________
- _________________________________
- Di alafo wonyi pelu oro ti o bamu ni isale
- Eni ti ko ni ewa rara _____
- Eni ti o maa n Daraya si enikeji _______
iii. Eni ti ko ni Igberaga rara ni ________
- Oro ti o lodi si ologbon ni ____________
- Omo ti o n na owo ni inakunaa ni _____
(oloyaya, apa, oburewa, omugo, onirele)
[mediator_tech]
THIRD TERM
SUBJECT: YORUBA CLASS: KILAASI KARUN-UN
Dahun gbogbo awon ibeere wonyi
- Aroko alariyanjiyan maa n da lori ______ (a) ise sise (b) iyan jija (d) ija jija
- Apeere oro oruko alaiseeka ni____(a) iyo (b) aga (d oluko
- Eniyan meloo ni o maa n ta ayo? (a) eniyan kan (b) eniyan meji (d) eniyan mewa
- Kini itumo foju lounje> (a) woran (b) gba oju mogi (d) foju
- Ise ni ____ise (a) oogun (b) bata (d) igo
- ____je apeere is ajumose (a) ona yiye (b) dida ilu ru (d) ole jija
- Omo ayo meloo ni o maa n wa ninu iho opon ayo kookan? (a) mefa (b) merin (d) meta
- ____je apeere oro aropo oruko (a) Jide (b) Awa (d) Aja
- Alaafin ni Oba ilu _____(a) Oyo (b) Oye (d) Oyan
- Ipinle meloo ni a ti lee ri aafin awon Oba alade ile Yoruba (a) meje (b) mefa (d) mejo
- Omo ayo meloo ni o wa ninu opon ayo lapapo? (a) Eejidinlaadota (b) Eejidinlogoji (d) (d) Ookanlelogun
- Kini owe wa fun? (a) ikilo (b) itanje (d) ise iyanu
- Anfaani ere ayo ni wipe , o maa n ____(a) je ki eniyan mo isiro (b) o maa n da opolo eniyan ru (d) o maa n dekun iba
- Apeere oro oruko aseeka ni ____(a) Tabili (b) suga (d) oyin
- “Juba ehoro” tumo si ___(a) salo (b) subu (d) sun
- Osu meloo ni o wa ninu odun? (a) osu meta (b) osu meji (d) osu mejila
- Ohun elo fun oge sise ni (a) alubosa (b) laali (d) Karosini
- Apeere ounje ile Yoruba ni ___(a) amala (b) semo (d) indomi
- Apeere oro oruko eran ko ni ___(a) pako (b) ewure (d) Amuga
- Tani olori ilu? (a) oluko (b) olopa (d) oba
- Aleebu ere ayo ni ___ (a) o maa n fi akoko sofo (b) o maa bu kun ewa wa (d) omaa n je ki ori pe
- Ipinle wo ni Ikeja wa? (a) ipinle oyo (b) ipinle eko (d) ipinle osun
- Orisii ise meloo ni a menuba ninu eko wa? (a) mefa (b) marun-un (d) merin
- Irinse agbe ni (a) oko (b) pakute (d) ibon
- Orisii agbe meloo ni o wa ___(a) meji (b) mefa (d) merin
- ____ ni o maa n ro ibon (a) ode (b) alagbede (d) akope
- Kini oruko ti a n pe awon onilu? (a) Ayan (b) olugbon (d) areas
- ____ni o maa n lo oko (a) ode (b) akope (d) agbe
- Ode ati ____ni o maa n to ofa (a) jagunjagun (b) onilu (d) agbe
- Ohun elo idana wo ni a maa fi n gbadura fun oko ati iyawo pe, won yoo bi omo pupo? (a) isu (b) iyo (D) ataare
IPIN KEJI: Dahun gbogbo awon ibeere wonyi
- Ko apeere oro-oruko aseeka marun-un
- ____________________________________ ii. ___________________________________
iii. ___________________________________iv. ___________________________________
- ____________________________________
- Ko apeere oro-oruko alaiseeka marun-un
- ____________________________________ ii. ___________________________________
iii. ___________________________________iv. ___________________________________
- ____________________________________
- so oruko ilu awon oba alade wonyi
- ooni – ___________________________ii. Deji – ___________________________
iii. Oba – ___________________________iv. Olubadan -__________________________
- Timi – ___________________________vi. Ataoja – ___________________________
vii. Ewi – __________________________ viii. Alake – _________________________
- Osemowe- _______________________x. Emia – _____________________________
- So ona marun ti awon okunrin ile Yoruba n gba se oge
- ____________________________________ ii. ___________________________________
iii. ___________________________________iv. ___________________________________
- ____________________________________
THIRD TERM
SUBJECT: YORUBA CLASS: KILAASI KEFA
Dahun gbogbo awon ibeere wonyi
- Itumi aropo lede geesi ni ____(a) subtraction (b) division (d) addition
- ____ni apeere oge sise laarin awon okunrin ni aye atijo (a) irun gige (b) laali lile (d) irun didi
- Okan lara aso okunrin ile Yoruba ni ___(a) agbada (b) tobi (d) gele
- Kin ni oro-ise ninu gbolohun yii Agbeke lo si oja (a) Agbeke (b) oja (d) lo
- Eebu alo ni ti ahun , abo bi ti ____(a) omo (b) ana (d) iyawo
- ______ni ege oro ti o lee ba eemi jade leekan soso (a) faweli (b) silebu (d) owe
- Kin ni o se Pataki julo ninu ohun elo idana (a) owo ori iyawo (b) obi (d) isu
- Kin ni ohun elo idana ti won fi n gbadura fun oko ati iyawo pe won maa bi omo pupo? (a) obi (b) orogbo (d) ataare
- Iro faweeli meloo ni o wa? (a) meji (b) meta (d) mewa
- Ami iro ohun meloo ni o wa? (a) meji (b) mefa (d) meta
- Kin ni oruko oba ile-ife (a) ooni (b) deji (d) ataoja
- Meloo ni leta faweeli airanmupe (a) leta meje (b) leta kan (d) leta mewa
- Leta faweeli aranmupe meloo ni o wa? (a) marun-un (b) mejila (d) mewa
- Apeere oro aponle ni ___(a) ropoto (b) sare (d) jeun
- ___je oruko amutorunwa (a) aina (b) bosede (d) joke
- Apeere asa oge sise ni ____(a) eyin pipa (b) moto wuwa (d) ile kiko
- A maa n fi ede ____(a) gbadura (b) jeun (d) gbale
- Tani olori ebi? (a) baba (b) egbon (d) iya
- Ojuse obi ni lati ____(a) pa omo won (b) toju omo won (d) fi iya je omo won
- Ise ijoba dara ju ise aladaani lo je aroko (a) oniroyin (b) asapejuwe (d) alariyanjiyan
- ____ni lilo ede tabi ami lati gbe ero okan eni jade (a) idanuro (b) ibara-eni soro (d) ala lila
- ___ni iye ona ti a n gba baa eni soro (a) meta (b) merin (d) marun-un
- Ewo ni o yato ninu awon ona ibara eni soro yii? (a) telifoonu (b) aale pipa (d) aroko
- Apeere ona ibara eni soro nipa lilo ohun elo olohun ni ___(a) oju (b) patako (d) ilu
- Aroko ni ___(a) ise to ni itumo akanlo (b) ise ti ko ni itumo (d) ise ti o le
- ______ni awon ti o lowo maa n lo fun irin ajo ni aye atijo (a) esin (b) ese (d) kanako
- Awon _____ni o maa n lo esin laye atijo (a) agbe (b) ode (d) olola
- _______ni o yato laarin awon wonyi (a) Baalu (b) Alupupu (d) Esin
- ______ni alagbede ma n fi finna (a) iwana (b) ewiri (d) emu
- Ohun ti awon alagbede fi maa n mu irin gbigbona ni (a) emu (b) ewiri (d) omo owu
Ipin keji: DAhun gbogbo awon ibeere wonyi.
- Daruko marun ninu ohun elo ibara eni soro ni aye atijo
- ____________________________________ ii. ___________________________________
iii. ___________________________________iv. ___________________________________
- ____________________________________
- Daruko marun ninu ohun elo ibara eni soro ni aye ode oni
- ____________________________________ ii. ___________________________________
iii. ___________________________________iv. ___________________________________
- ____________________________________
- Pin awon oro wonyi si silebu
- Aderibigbe – _________________________ ii. Agbalagba- _______________________
iii. Jegede – ____________________________iv. Agbabiaka – ________________________
- Alagbede- ____________________________
- Daruko ounje abinibi ile Yoruba marun-un
- ____________________________________ ii. ___________________________________
iii. ___________________________________iv. ___________________________________
- ____________________________________
- Daruko aso ile Yoruba marun-un
- ____________________________________ ii. ___________________________________
iii. ___________________________________iv. ___________________________________
- ____________________________________
- ko leta faweeli aranmupe marun-un
- ____________________________________ ii. ___________________________________
iii. ___________________________________iv. ___________________________________
- ____________________________________
DOWNLOAD THIRD TERM EXAMINATION FOR PRIMARY SCHOOLS PRIMARY 1 TO PRIMARY 6 YORUBA
SS 2 THIRD TERM YORUBA LESSON NOTES
Third Term SS 1 Lesson Notes Yoruba