SECOND TERM EXAMINATION CLASS: PRIMARY 5 SUBJECT: YORUBA LANGUAGE
SECOND TERM EXAMINATION
CLASS: PRIMARY 5 SUBJECT: YORUBA LANGUAGE
NAME:………………………………………………………………………………
Ojo ojumo ni Ade n fo eyin re
Bo ba fo o tan
A we gbogbo ara re da saka
Nitori eeri ara
Ade ki i rinrin idoti
Eekanna re a mo tonitoni
Aso re a mo nini ni gbogbo igba
Ma a gbeyin rira laaye
Arun ti gbabe eekanna ko kere
Ki aisan ma ba gbe o de
Ibeere
- ______________ ni Ade n fo eyin re (a) ose kan (b) ojojumo (c) osu meji
- Ade ki i rinrin ___________ (a) mimo (b) janduku (c) idoti
- Arun ti nbe labe __________ ko kere (a) eekanna (b) irun (c) abia
- A gbodo ma we ara ko ___________ (a) ma a yo (b) da saka (c) ma bo
- Ti a ba we dada, __________ o ni gbe wa de (a) erepa (b) orun (c) aisan
- Ni ile Yoruba, Agbada je aso _________ (a) okunrin (b) obinrin (c) eranko
- Gele je aso ____________ (a) isere (b) imurode (c) ise
- Osu _________ ni osu ope (a) kejila (b) kini (c) kefa
- Orisirisi aso ni Yoruba ma n wo ki oyinbo to de (a) Beeni (b) Beeko
- __________ je ounje ile Yoruba (a) sharwama (b) chicken and chips (c) amala
Theory:
Dahun gbogbo ibeere wonyii
Ko onka ni ede Yoruba (1 – 10)
1 =
2 =
3 =
4 =
5 =
6 =
7 =
8 =
9 =
10 =
Ko awon ojo wonyi ni ede yoruba
Sunday _______________________
Monday _______________________
Tuesday _______________________
Wednesday ______________________
Thursday _______________________
Friday _______________________
Saturday _______________________
Daruko osu marun ni ile Yoruba ati oruko geesi won