SECOND TERM EXAMINATION YORUBA PRIMARY 1
CLASS: PRIMARY 1
SUBJECT: YORUBA
NAME:………………………………………………………………………………..
Di awon alafo won yii
- Ojo __________ ki baba re (a) o duro (b) o dubule (d) o dobale
- Aina _________ ki iya re. (a) kunle (b) sun (d) joko
- ___________ ni Ojo wa nigba ti o fun baba re ni ada (a) ijoko (b) iteriba (d) sun
- Awon ___________ Adeolu ni won sare lo gba eru ori Adeolu (a)Egbon (b) Iyekan (d) Aburo
- ga____ri (a) d (b) a (d) u
- ire ____e (a) c (b) k (d) gh
- Agb____do (a) a (b) e (d) g
- Ab____la (a) e (b) p (d) gh
- A____an (a) u (b) d (d) k
- Ib____n (a) w (b) c (d) o
- Inu _________ ni eleye n gbe (a) ita (b) igboro (d) ile
- Eyele ki I gbe inu ____________ (a) oko (b) igbe (d) ode
- O ___________ to ni to ni (a) je (b) mo (d) wo
- O fi ____________toni toni bora (a) ori (b) iye (d) apa
- ___________ leyele laarin awon eye. (a)idoti (b) orun n (d)Afinju
CLASS: PRIMARY 1
SUBJECT: CREATIVE ARTS
NAME:………………………………………………………………………………..
Draw and colour Nigeria Flag
Colour this chair and head-rest with two colours