Yoruba JSS 2 FIRST TERM E-LEARNING SCHEMES OF WORK LESSON NOTES

YORUBA LANGUAGE SCHEME OF WORK JSS 2 

 

  1. SISE ATUNYEWO FONOLOJI EDE YORUBA
  2. AKOLE ISE EYA GBOLOHUN NIPA ISE WON
  3. EYA GBOLOHUN
  4. Gbolohun Ede Yoruba nipa fifi oju ihun wo o.
  5. Onka Yoruba (101 – 300)
  6. Onka Yoruba (300 – 500)
  7. AKAYE OLORO GEERE
  8. ASA ISOMOLORUKO
  9. IYATO TI O DE BA SIPELI FAWELI
  10. Kiko Yoruba ni ilana Akoto Ode-Oni
  11. 1st Term Examination YORUBA JSS 2

 

 

 

ODUN IGBEKO JSS TWO

ISE OOJO FUN SAA KIN-IN-NI

   

Sise atunyewo fonoloji ede Yoruba

Atunyewo awon asa ninu ise olodun kin-in-ni

Atunyewo awon ewi alohun yoruba

Eya gbolohun nipa ise won

Asa igbeyawo ni ile Yoruba

Kika iwe apileko ti ijoba yan

Eya gbolohun

Asa igbeyawo ni ile Yoruba (igbeyawo ode-oni)

Kika iwe apileko oloro geere

Gbolohun ede Yoruba nipa fifi oju ihun wo o

Sise akanse ise awujo Yoruba (project)

Litireso alohun to je mo ayeye

Onka Yoruba (101-300)

Ise akanse kan ni awujo (project)

Litireso alohun to je mo ayeye

Kika iwe apileko ti ijoba yan

Onka Yoruba (300-500)

Sise itoju oyun ni ona abinibi ati ode-oni

Akaye oloro geere

Ise omo bibi (oro idile baba olomo)

Kika iwe apileko ti ijoba yan

Akaye oloro geere

Asa isomoloruko

Kika iwe apileko ti ijoba yan

Akoto 

Igbagbo Yoruba nipa orisirisi owe ile Yoruba

Kika iwe apileko oloro geere ti ijoba yan

Kiko Yoruba ni ilana akoto ode-oni

Orisirisi oruko ile Yoruba (igbagbo Yoruba nipa abiku