Third Term Examinations Primary 1 Yoruba
THIRD TERM
SUBJECT: YORUBA CLASS: KILAASI KINNI
Dahun gbogbo awon ibeere wonyi
- Ori ibo ni a maa n sun si? (a) ori odo (b) ori sitoofu (d) ori beedi
- Bi mo ba kawe mi ____ mi a dun koko ka (a) bata (b) iwe (d) obe
- Apeere nnkan sise ni _____ (a) igi (b) dobale (d) aga
- ____ ni o le segun arun gbogbo (a) imototo (b) beedi (d) rula
- Nje o dara ki a maa a ja? (a) o dara (b) ko dara (d) n ko mo
- Kini 11 ni onka Yoruba? (a) Eejila (b) Eefa (d) ookanla
- Kini Aiku ni ede geesi? (a) Sunday (b) Tuesday (c) Friday
- Obinrin maa n ___irun won (a) di (b) jo (d) sa
- okunrin maa n ____irun won (a) se (b) ge (d) pin
- Bawo ni a se n ki eniyan ni osan? (a) e kale (b) e kuurole (d) e kaasan
Kini oruko awon aworan wonyii:-
IPIN KEJI: Dahun awon ibeere wonyi . Ko leta alifabeeti lati ori A-S
a, ________, d , _______, e, _________, g, ________, h, ________,j, __________, i,_______, n, ______, o, _________, r.
so onka wonyi papo pelu nomba ti o ye.
14 =
21 =
50 =
8 =
61 =