Yoruba Primary 4 First Term Examinations

FIRST TERM EXAMINATION 2021/2022

CLASS: PRIMARY 4

SUBJECT: YORUBA LANGUAGE

NAME:……………………………………………………

IWE KIKA: ASIMU OLE

1.) __________ ni oruko oja ilu pokii (a) ikilo (b) oroorun (d) ayelu

2.) Ohun ti o se akoba fun pokii ni pe _____________

(a) o ni ore pupo (b) o nra epa je (d) o nlo si oja ayelu

3.) Eni ti o bu Pokii pe “Lanboroki, oju re jaa na” ni __________

(a) Ore Pokii kan (b) omo ilu ikilo (d) Aladugbo Pokii kan

4.) _______________ ni eni ti won fa omo ti o jale gan’an fun lati da seria fun-un

(a) Olopaa (b) Ore Pokii (d) ara oja ayelu

5.) Kini oruko Aladugbo Pokii ti omu-un pada sile? (a) Adio (b) Akanni (d) Alao

 

 

 

IWE KIKA: OUNJE KARI AYE:

EGE ATI AGBADO

i.) Eni ti o so pe paki ni won fi nyan gaari ni _________ (a) Bunmi (b) Wale (d) Baba

ii.) Ewo ni a nfi paki se ninu awon nnkan wonyii (a) kango (b) fufu (d) Abari

iii.) Bi agbado ba parada, a maa di ____________ (a) ogi (b) lafun (d) fufu

iv.) Ewo ni kii se ooto?

(a) Igi ege ni a maa ngbin (b) A maa nse iru ege kan je (d) agbado ni a fi nse fufu

v.) Ko ounje meji ti o mo ti a nfi agbado se

(a) _______________________________ (b) _______________________________

 

 

IWE KIKA: ADUNBI ATI IYA RE

1.) Omo melo ni Iya Adubi bi? (a) omo meta (b) omo kan (d) omo merin

2.) Iru owo wo ni Awele nse (a) onta isu (b) o ngba aaru (d) o nta eja

3.) Ona wo ni Olorun fi pon Adubi le? (a) Adubi gbe odo oyinbo oniwaasu

(b) Adubi ba iya re ta eja (d) Adubi lo yunifasiti Ibadan

4.) Kii ni o gbe Adubi de odo oyinbo oniwaasu

(a) Ise omo odo (b) O fe kawe sii (d) ko mo eniyan kankan

5.) Kin ni koje ki Awele le paaro aso bi awon elegbe re

(a) ko feran oge (b) aso won ni ilu won (d) ere oja re ko po

 

 

ILU ORIN ATI IJO

1.) ________ maa nfi ise ilu jogun ni (a) awo (b) ayan (d) oloya

2.) A ko lefi ilu _____________ (a) taniji (b) kede (d) ji oku

3.) Awon wo lo maa njo ijo jelenke (a) agbalagba (b) ipeere (d) odo

4.) Leyin ti a ba gbo iro ilu ati orin, kini a o tun maa reti

(a) ere onijo (b) owo onijo (d) ijo jijo

5.) So meji ninu iwulo ilu

(a) _______________________________

(b) _______________________________

 

 

Yoruba First Term Examination Primary 3

 

YORUBA LANGUAGE PRIMARY 2

 

 

OWE ILE YORUBA. Proverbs in Yoruba Land

 

.

 

 

 

.

 

 

 

 

 

 

 

 

 

 

Spread the word if you find this helpful! Click on any social media icon to share