YORUBA LANGUAGE PRIMARY 2

FIRST TERM EXAMINATION 

CLASS: PRIMARY 2 SUBJECT: YORUBA LANGUAGE

NAME:……………………………………………………………………………………

  1. Orin akomo niwa: – Omo rere
  2. Omo rere kii ___________ (a) puro (b) sun
  3. Omo rere kii ___________ (a) jo (b) jale
  4. Omo rere kii ___________ (a) sole (b) kawe
  5. Omo rere kii ___________ (a) sise (b) seke
  6. Omo rere kii ___________ (a) seka (b) kawe
  7. Iwa omoluabi: – Itoju ati Oore Sise
  8. __________ nse baba Aina (a) Aisan (b) ebi
  9. __________ wa kii (a) Ajayi (b) Aina
  10. Iya __________ sa awon aso re si ita (a) Ade (b) Sola
  11. ________ nba ka awon aso naa (a) Kemi (b) Tola
  12. ___________ ati mama re nlo sode (a) ojo (b) ige
  13. Iroyin ati Asogba
  14. Ile-eko mi dara:- Tani o nsoro (a) Tunde (b) Alabi
  15. Bee ni, sugbon ko dara to ile eko ti wa:- Tani o fesi oro yii (a) Alaba (b) Tunde
  16. Woo bi ododo se po yi kii aasi ma ka:- Tani o tun soro (a) Tunde (b) Alaba
  17. Igi ti o lewa po ni ile-eko temi ju tire lo:- Tani o nso ro yii (a) Alaba (b) Tunde
  18. Wo maalu ti baba mi ra:- Tani o nsoro yii (a) Tunde (b) Alaba
  19. Aropo Imototo
  20. Fo _______ re bi o baji (a) eyin (b) apa
  21. Gba ______ re pelu (a) irun (b) ayika
  22. Ge ______ re lasiko toye (a) Ese (b) Irun
  23. ______ ti ngbe abe eekannaa ko kere (a) Alaafia (b) Arun
  24. Dakun dabo, jowo, wo ______ to mo (a) Aso (b) ago
Spread the word if you find this helpful! Click on any social media icon to share