1 Oókan Oonka Ede Yoruba
Pry two
Ose kefa
Akole:
onka ni ede Yoruba lati ori ookan de ogbon
1- Ookan
2- Eeji
3- Eeta
4- Eerin
5- Aarun
6- Eefa
7- Eeje
8- Eejo
9- Ẹesan
10- Ewaa
11- Okanla
12- Ejila
13- Etala
14- Erinla
15- Aarundinlogun
16- Eerindinlogun
17- Eetadinlogun
18- Ejidinlogun
19- Okandinlogun
20- ogun-un
21- Okanlelogun
22- Ejilelogun
23- Etalelogun
24- Erinlelogun
25- Arundinlogbon
26- Erindinlogbon
27- Etadinlogbon
28- Ẹjidinlogbon
29- Okandinlogbon
30- Ogbon
Yoruba Language Jss 1 First Term Examinations
Ise kilaasi
Kinni oruko awon nomba yii ni Ede yoruba
1. 21 (a)etalelogun (b)okanlelogun
2. 23 (a)ejilelogun (b)etalelogun
3. 20 (a)Ogun (b)ogbon
4. 25 (a)arundinlogun (b)arundinlogbon
5. 27 (a)ogbon (b)etadinlogbon
.