Yoruba Pry 2 Second Term

SECOND TERM EXAM

BASIC 2

 

YORUBA

 

Silebu mélo lowa nínú àwọn ọ̀rọ̀ wọn yii ?

 

(1) Ade (a) meji (b) meta

(2) Ologbon (b) meji (b) meta

(3) ilu (a) meji (b) meta

(4) Panla (a) meji (b) meta

(5)ila (a) meji (b)meta

(6)A gbodo fowo bi a ba fe jeun. Beeni / Beeko

(7) A gbọ́dọ̀ fò ẹnu wa lowuro . Beeni / Beeko

(8) A gbọ́dọ̀ bó ouje wa Beeni / Beeko

(9) A gbodo gbadura sounje wa ka to je Beeni / Beeko

(10) Ma se so oro bi o ban jeun Beeni / Beeko

 

THOERY

(1). Ko orin yii :- We ki o mo,

 

(2). Daruko awon nnkan meji to wa ni arin ilu

 

(3). Dárúkọ yara meji ninu ile

(4) Ko ojuse obi meji sii omo