Oge Ṣíṣe ni Ile Yorùbá Jss 1 First Term

Oge Ṣíṣe ni Ile Yorùbá Jss 1 First Term
Àwọn ọ̀nà tí a ngba ṣe oge ni ile Yoruba ni ìwọ̀nyí

1. Osun kíkún
2. Laali l’île
3. Tiro l’île : Àti òkùnrùn àti obìnrin ni ó feran láti máa lé tiro. Ebu didu ni à man fii lè tiro. Tiro líle man nko idoti kúrò nínú ojú láti jẹ kii ojú gun régé
4. Etí lílu : Àwọn obìnrin ni ó ní àṣà etí lílu. Ọkùnrin kii lu etí ni ile Yoruba. Bí etí lílu shee wá bẹẹni ímu lílu wàá. Yorùbá kii lu ète tàbí àwọn. Eleyi lòdì sí àṣà àti ìṣe ilé Yoruba.
5. Eeyin tipa : Ásà yìí kò fi bẹẹ gbajumo ni ile Yoruba ni. Ikọ̀ ni wọn man fi paayin ni ile Yorùbá. Eyin iwájú ni wọn man pá ni ayé àtijó
6. Irun dídì àti orí fífà : Obìnrin ni ó ní irun dídì. Àwọn ọkùnrin ní wón ní odi fífà
Ásà yìí sí wàá di wákàtí owó yìí.
Àpẹẹrẹ irun dídì ni ipako elédè, suku, kolẹ́sẹ́, àti bébé bèbè lọ
Àwọn okùnrin man faa ori wọn kodoro
7. Aso wíwò : imura Yoruba yàtò sii imura àwọn ẹ̀yà toku. Buba àti Sokoto, ewu àti dandogo, Sokoto ati gbayire
Àwon obìnrin yìí wọ̀ ìró àti Buba àti gèlè