Yoruba Primary 5 First Term Examination

FIRST TERM EXAMINATION 2021/2022

CLASS: PRIMARY 5                                                     

SUBJECT: YORUBA LANGUAGE

 

NAME:…………………………………………

 

ERE IDARAYA: ERE AYO

  1. Omo Ayo me lo ni o maa nwa ni oju opon ayo lapapo(a) mejidinladota (b) merinlelogun (d) marundinlogoji
  2. Asiko wo ni a maa nta Ayo ni ile yoruba (a) owuro (b) ale (d) irole
  3. Kii ni awo omo Ayo (a) Awo eeru (b) Awo eweko (d) Awo buulu
  4. Omo Ayo melon lo nwa ninu iho Kankan (a) mejo  (b) mesan (d) merin
  5. Apa ____________ ni a maa nta ayo si (a) osi (b) otun (d) eyin

 

 

Ayo Olopon Akole:Ere idaraya ni ile yoruba(ere ayo

 

ORIKI ATI ILANA KIKO AROKO YORUBA PELU APEERE.

ERE IDARAYA: ERE AARIN

  1. Awon wo la maa nba nidi arin tita (a) obinrin (b) gende (d) omo-weere
  2. Kin ni eso arin fi awo jo (a) or obo (b) ayo     (d) paanu to dogun-un
  3. Ona meji ti a le fi ta arin ni _______ (a) ori ila ati inu ape arin(b) inu opon ayo ati ori ila                  (d) ori eni arin ati inu iho alatako
  4. Eso wo ni a le lo dipo eso arin (a) oronbo wewe (b) osan mimu     (d) eyin
  5. Ibo ni a ti nse ere arin (a) ori eni (b) ita gbangba   (d) ori pakiti

 

GIRAMA: AKANLO EDE:

  1. Kini itumo akanlo ede yii: Fi aake kori:(a) Fi aake si ori     (b) ki eniyan ko jale lati se nnkan  (d) ki eniyan buru
  2. Kini itumo akanlo ede yii : Fomo yo (a) Se ase yori (b) Fa omo jade     (d) yo omo lo
  3. Kini itumo akanlo ede yii: Edun arinle
  4. edun ti o nrin nile (b) eni ti o ti lowo ri sugbon ti o pada raago  (d) edun ti o po ganan
  5. Kini itumo akanlo ede yii: Epa ko boro mo(a) Ko si epa mo   (b) epa wa ninu oro   (d) Ko si atunse mo
  6. Kini itumo akanlo ede yii: Kan oju abe ni ko
  7. ka soro pato si ibi ti oro wa (b) ki abe mu daadaa   (d) so oro si abe

 

OWE ILE YORUBA:  

Pari owe yii

  1. Bami na omo mi _____ (a) owo lo ndun iya e (b) o se ni (d) Ko de inu olomo
  2. Pari owe yii:- Agba kii nwa loja ________________________(a) Kori omo tuntun wo   (b) Kii inu obi ni    (d) Ko maa se lagba lagba
  3. Pari owe yii:- Aja ti yoo sonu ________ (a) Arin lo ni (b) kii gbo fere olode (d) a wa gbo lo
  4. Pari owe yii:- Eni ti yoo je oyin inu apata _____________
  5. kii now enu aake (b) a fo apata ni (d) aake a ro ni
  6. Pari owe yii:- Ile ti a fi ito mo _______ (a) a dara si ni (b) nte gun a gbe lo  (d) iri ni yoo wo

 

 

Yoruba Primary 6 First Term Examinations

 

 

First Term Primary 4 Examinations Yoruba

 

.

 

 

.

Spread the word if you find this helpful! Click on any social media icon to share