AMI OHUN ONISILEBU MEJI
Subject : Yoruba
Class : Jss 2
Term : Third Term
Week : Week 7
Topic :
EDE Leta aigbefe (1) ohun ti leta aigbefe je (2) awon ilana ti a le gba ko le
ta aigbefe-adireesi, deeti,adireesi agbaleta,ikini ibere,koko leta, ipari.
ASA Awon ohun mimo ninu esin ibile- igba funfun,ileke funfun, awo funfun
Ogiri funfun abbl.
OSE KEJE
EDE
AMI OHUN ONISILEBU MEJI
(fi ara bale daadaa pe awon oro wonyi pelu ami ori won)
AMI OKE AMI ISALE AMI AARIN
sibi iji ife
Kunle igba omo
Wale ego ire
Batani kin-in-ni re mi
(fi ara bale daadaa pe awon oro wonyi pelu ami ori won)
awo ile ise ipon
ile itun aja apa
aje ede egbe ere
ewe ibi imi odo
ogbo oro oso ose
Batani keji re do
(fi ara bale daadaa pe awon oro wonyi pelu ami ori won)
aba ajo ida imo
aje ila ola ife
ere iko ibe amo
are ile iwi ige
Batani keta do mi
(fi ara bale daadaa pe awon oro wonyi pelu ami ori won)
egbe ore opa ota
ila otun aba ada
ilu agba Aja ala
ana apa ara amo
Batani kerin do do
(fi ara bale daadaa pe awon oro wonyi pelu ami ori won)
ebe ese eje efe
ele ala aja apa
ija ila ifa ika
Batani karun-un do re
(fi ara bale daadaa pe awon oro wonyi pelu ami ori won)
ida Dada aga obo
ajo ole obe oje
ope owe.
ÌWÉ ÀKÀTILÉWÁ
Oybamji Musstapha (2013) EKO EDE YORUBA TITUN J.S.S.1 University Press Plc. Oju iwe 91-99.
IGBELEWON
- Fi ami si awon oro wonyi lori: ile, ile, ile, aso, aso, ise, ise.
Ko ohun elo inu ile mewaa sile ki o si fi ami si won lori.
ASA
ÀWON EYA YORÙBÁ ÀTI IBI TÍ WÓN TÈDÓ SI
A gbo pe Okanbi ni apele re n je Ide-ko-se-e-ro-aake ni omo kan soso ti o bi. Okunrin ni sugbon meje ni awon omo Okanbi. Obinrin meji ni Okanbi koko bi awon marun-un yooku si je okunrin. Owu ni omo re akoko. Oun ni o se awon Owu do. Omo re keji ti o je obinrin ni Alaketu, oun ni o sit e awon Ketu do. Awon woni won n gbe n iha ariwa ile Olominira Binni.
Omo re keta ti o si je okunrin ni o tea won Edo sile. awon wonyi ni o n gbe ipinle Edo lonii. Omo kerin karun-un ati ekefa ti won je okunrin ni Orangun, Onisabe, ati Olupopo. Eyi ti o si abikeyin ni Odede ti apele re n je Oranmiyan. Oun ni a gbo pe o tea won Yoruba Oyo sile. akoni Odede. Ise ode ati jagunjagun ni o n se.
Lojo kan ni o pe awon egbon re pe ki ki awon lo gba esan iku to pa baba won (Lamurudu) ati ile esin ti le baba won niluu Meka. Awon egbon re ko lo sugbon nitori pe o je akoni, o lo.
Sugbon o ba isoro pade loju ona. Ko le de Meka itiju yii ko je ki o pada de Ile-Ife. Dipo bee o tedo si ilu ibomiran. Ilu yii in a mo si Oyo. Oyo ni o si n gbe ja awon ilu miiran logun ti o si n gba won mora. Nipa bayi o di wi pe ilu Oyo bere si nip o si.
Itan miiran ti a tun bo lati enu Alufa Johnson so pe nigba ti Okanbi ku, awon omo re ti won je okunrin ati obinrin pin ohun ini re sebi eniyan ba dagba omo eni ni i jogun eni.
Oba Ibini jogun owo
Orangun jogun aya.
Onisabee jogun eran-osin
Onipopo jogun ileke
Olowu jogun aso/ewu
Alaketu jogun ade
Aburo won patapata ko si nile won ti pin gbogbo ogun tan ki o de. O sise ode lo. Oba Bini lo tedo si ipinle Edo. Orangun, Onisabe, Olupopo, Alaketu lo tedo si ibi ti awon omo won wa lonii.
Bi o ti le je pe omo iya ni gbogbo omo kaaaro-oo-jiire, sibe won pin si orisiirisii eya ti ede won si yato diedie si ara won. Orisii ede ti won n so naa ni eka-ede. Sugbon sa, gbogbo omo Yoruba ni o ni ede ajumolo kan ti a le pe ni ojulowo Yoruba ede ajumolo. Ede eya Yoruba Oyo ni o sunmo ojulowo Yoruba naa bi o ti le je wi pe ohun naa ni aleebu tire gege bi eka-ede. Ojulowo Yoruba naa tabi Yoruba ajumolo yii ni a fi n ko omo ni ile eko. ohun ni a fi n ko orisiirisii iwe lati ori leta si ara eni titi de ori iwe ti a n ka.
Ipinle meje ni o je ipinle Yoruba ni orile-ede Naijiria, ni abe awon ipinle yii ni a ri awon eya Yoruba miiran pelu eka ede ti o yato si ara won. Apeere awon ipinle naa ni: Ipinle Oyo, Eko, Ogun, Osun, Ondo, Ekiti ati Kwara. Ni abe ipinle Ogun ni a ti le ri: Egba, Egbado/Yewa, awori. Ni abe Oyo a ri eya ………..
ÈYÀ YORÙBÁ ÌLÚ ABÉ WON
Oyo Òyó, Ògbómosó, Ibadan ….
Egbado/Yewa Ilaro, Ado odo, Imeko, Igbogila
Egba Abeokuta, Gbagura, Owu, Oke ona
Ijebu ìjèbú-ode, ìjèbú igbo, àgo ìwoyè,
sàgamu, ìperu, epe
Ilesa ìjèbú ijèsà, ibokun, èsà okè, ipetu ijèsà
IGBELEWON:
- Ko ilu Yoruba mewaa otooto.
- Fi eka ede wonyi tun awon ede Yoruba ajumolo yii: (Ibarapa, Ekiti, Ijebu): ori, imu, enu, eko ati isu.
IWE AKATILEWA
Oyembamji Mustapha (2009) Eko Ede Yoruba Titun (J.s.s 1) University Press Plc. Oju iwe 53-62.
LITIRESO
KIKA IWE TI IJOBA YAN
APAPO IGBELEWON
- Se alaye lekun rere lori ami ohun ede Yoruba pelu apeere mejimeji fun okookan.
- Ko eya Yoruba mejo sile.
IGBELEWON
- Ko asa yoruba mewaa sile.
- Salaye eyo kan ninu asa yoruba ti o ko sile.
IWE AKATILEWA
Oyebamji Mustapha (2009) Eko Ede Yorba Titun (J.S.S.1) oju iwe 12-13 University Press Plc.
ISE ASETILEWA
- Leta …….ni leta iwase. (a) ore (b) gbefe (d) alaigbefe.
- Ibi ti adiresi eni ti a n ko leta si maa n wa ni….. (a) isale leta patapata ni apa osi (b) oke leta ni apa otun (d) oke leta ni apa osi
- Adiresi eni ti n ko leta maa n wa ni ….. (a) isale leta ni apa otun (b) oke leta ni apa osi (d) oke leta ni apa otun.
- ______ni ohun mimo akoko ninu esin abalaye. (a) ojubo (b) ile aworo (d) omi orisa (e) eni to n pon omi.
- Awon ti o maa n pe ‘ori’ ni eri ni. (a) Eko (b) Ondo (d) Ibarapa (e) Ikeja.
- Awon ti won maa n pe ‘isu’ ni ‘usu’ ni (a) Eko (b) Ondo (d) Ibarapa (e) Ijesa.
APA KEJI
- Ko adireesi ile re ati adireesi ijoba ibile re sile.
- Salaye lori eka ede ati ede ajumolo pelu apeere.