OWE ILE YORUBA (Pry 6)

Pry six

Akole: OWE ILE YORUBA

 

  1. Eni ti yoo je oyin inu apata,koni wo enu aake

 

  1. Oju ti yoo baa ni kale, kin ti owuro sepin

 

  1. ile ti afi to omo,iri ni yoo wo

 

  1. kekere la ti npeka iroko,toba dagba tan apa kii nka

 

  1. Bi omode mo owo we,aba agba jeun

 

 

Ise kilaasi

Pari awon owe wonyii

 

  1. Eni ti yoo je oyin inu apata _____(a)kin wo enu aake (b) ase wahala gan

 

2.Oju ti yoo ba ni kale____(a) a fo ni (b)kin ti owuro sepin

 

  1. Ile ti afi to omo ____(a) iri ni yoo wo (b) a dara si nii

 

  1. Kekere latin peka Iroko_____(a)koto dagba (b)to ba dagba tan apa koni kaa mo

 

  1. Bi omode baa mowo we_____(a) aba agba jeun (b)owo e amo nii
Spread the word if you find this helpful! Click on any social media icon to share