Asa igbeyawo ni ile Yoruba

Class: Pry five

Subject: Yoruba Studies

 

Akole: Asa igbeyawo ni ile Yoruba

 

Orisi ona marun ni asa igbeyawo pin si awon ona naa ni awon wonyii

 

  1. Igbeyawo ni aye atijo
  2. Igbeyawo no aye ode oni
  3. Igbeyawo ni kootu
  4. Igbeyawo ni soosi
  5. Igbeyawo ni mosalasi.

 

IGBEYAWO NI AYE ODE ONI.

Orisi ona meje ni igbeyawo, ni aye ode oni. Awon ona naa ni awon wonyii:

 

  1. Ifojusode
  2. Alarin na
  3. Ishihun tabi ijohen
  4. I toro
  5. Diana
  6. Ipalemo
  7. Igbeyawo

IFOJUSODE

ti omokunrin ba ti balaga,yoo beere sini fojusode boya yoo ri omobinrin ti o rewa, yoo toju ara ti o ba fi oju kan wundia to joju ni gbese ise fi ise alarina.

ALARINA

Alarina ni iko ti o gboke gbodo laarin omokunrin ati omobinrin ti won fefe ara won,ise alarina ni lati wadi idile ti omo binrin ti wa.

Ti oba wadi ti ori pe idile dardara ni oti wa alarina yoo wa la oju agi si agi idini iyi ti anse pa lowe pe ti oko ba moju aya tan alarina a moju

 

ISHIHUN TABI IJOHEN

Oro ti omokunrin ba baa omobinrin so gbigba ti omobinrin baa gba si omokunrin lenu ni awa yoruba pe ni isihun tabi ijohen

 

ITORO

leyi ti omobinrin ba ti johen tan, omokunrin yoo wa so fun awon obi re lati lo ba toro omo.

Owuro kutukutu ni ama lontoro omo ni ile Yoruba baba omokunrin yoo gbe oti oyinbo kan dani lati fii toro mo

 

IDANA

leyin ti won baa ti toro omo tan ohun ti oku ni idana.ile omokunrin ni won yoo ti ko awon ohun idana wa awon kan jije ati mimu ati ohun tii won yoo fise adura fun tokotaya idana yii se pataki ose koko ibe ni awon idile mejeji yoo ti pade ni ekunrere.

 

IPALEMO

Leyin ti won ba ti dana tan iyawo yoo beere si ji pale mo die die lo sile oko re oko iyawo yoo fun iyawo re ni owo yantuuru ti yoo fi ra ohun ti yoo malo ni ile oko tabi ki oran eniyan ni idile re ki ora,kiwon kowa fun iyawo re

 

IGBEYAWO

Leyin ti iyawo baa ti paleemo tan, oko iyawo yoo wa mu ojo igbeyawo loosi oda awon ana re oko iyawo yoo wa se gudugudu meje ati yaya mefa.Apeje ama lo ni idile oko ati idile iyawo. Ni ale ojo igbeyawo oko iyawo gbodo sunmo iyawo ni afe moju kole iru iyawo to kowole.

 

Ise kilaasi

 

  1. ____________ ni iko ti o gboke gbodo laarin omokunrin ati omobinrin ti won fefe ara won.(a)Alarina. (b)Alamojuto
  2. Oro ti omokunrin ba baa omobirin so,gbigba ti omobinrin gba si omokunrin lenu ni ape ni ______________(a)Igberaga. (b)ishihun tabi ijohen
  3. Igbawo no ama lo ntooro omo ni ile Yoruba(a) owuro kutukutu. (b) ale patapata.
  4. Kini anpe ni ibale? __________________(a) gba oju omobinrin(b) gba ogo omobinrin
  5. Ni akooko ti baba omobinrin se adua fun omo re omobinrin yoo ma sunkun ekun kini anpe ______________(a) ekun ayo. (b) ekun iyawo

 

 

Evaluation

  1. Ifojusode ni __________ ti o gba omokunrin si omobinrin (a) isihun tabi ijohen (b) alarina
  2. Ni ile Yoruba, igbeyawo ni aye ode ____________ (a) owuro kutukutu (b) ale patapata
  3. Oro ti omokunrin ba baa omobinrin so, gbigba ti omobinrin baa gba si omokunrin lenu ni awa yoruba pe ni _____________ (a) igberaga (b) isihun tabi ijohen
  4. Kini anpe ni ibale? (a) gba oju omobinrin (b) gba ogo omobinrin
  5. Leyin ti won baa ti dana tan, iyawo yoo beere si ji pale mo die die lo sile oko re (a) ijohen (b) ipalemo
  6. Leyin ti omobinrin ba ti johen tan, omokunrin yoo wa so fun awon obi re lati lo ba ____________ omo (a) toro (b) isihun
  7. Leyin ti won baa ti toro omo tan, ohun ti oku ni ____________ (a) alarina (b) idana
  8. Ni ale ojo igbeyawo, oko iyawo gbodo sunmo iyawo ni afe moju kole iru iyawo to ____________ (a) kowo (b) kowole
  9. Ti oba wadi ti ori pe idile dardara ni oti wa alarina yoo wa la oju agi si agi idini iyi ti anse pa lowe pe ti oko ba moju aya tan _____________ (a) ijohen (b) alarina
  10. Ni akooko ti baba omobinrin se adua fun omo re, omobinrin yoo ma sunkun ekun kini anpe ni ilera re? (a) idana (b) igbeyawo