IDANWO TAAMU KEJI SUBJECT: YORUBA CLASS: KEFA YORUBA SECOND TERM EXAMINATION

IDANWO TAAMU KEJI

SUBJECT: YORUBA CLASS: KARUN-UN

Dahun gbogbo awon ibeere wonyiI.

  1. Eniyan meloo ni o kopa ninu ayoka onisorogbesi ti a ka (Efunsetan Aniwura) (a)meji (b) meta (d) mewa
  2. Ta ni won n soro nipa re ninu ayoka yi (a)osuntunde (b) itawuyi (d) kolade
  3. Awon wo ni won fi ija tuka (a) Awero ati itawuyi (b) Adetutu ati Itawuyi (d) Akano ati kike
  4. Ta ni ohun re n gbon ninu ayoka yii? (a) Adetutu (b) Bola (d) Awero
  5. Orin to wa fun ayeye olokan -o-jokan ni

(a) orin oye (b) orin aro (d) orin ibile

  1. Ibi ayeye ti won ko tile e ko orin ibile ni

(a) oku ofo (b) igbeyawo (d) isomoloruko

Nibi ayeye wo ni a ti n gbo awon orin wonyi

  1. Iya awa lo

O rorun idera (a) oku agba (b) isile (d) igbeyawo

  1. Omo la o fi gbe eee, omo la o fi gbe, owo osun lowo awa je orin (a) ikomojade /isomoloruko (b) ajodun (d) isile
  2. O di koro oye naa koole wa (a) igbeyawo (b)odun ibile (d) ayeye oye
  3. Awon ti o gbodo fowosi igbeyawo ni ____ (a) alarina (b) obi omo ati molebi (d) iyawo nikan
  4. Ewi iyawo fun idagbere ni ___(a) orin iyawo (b) itoro (c) Ekun iyawo
  5. Ohun elo idana ni wonyi ayafi (a) isu (b) igi

(d) obi

  1. Ewi ti o n dari eto isomoloruko ninu idile ni (a) Baale ile (b) Baba omo (d) iya omo
  2. Lara eroja isomoloruko ni wonyi ayafi

(a) atarodo (b) obi (d) oyin

  1. Ojo keloo ni a maa n so omo loruko ni ile Yoruba? (a) ojo keta (b) ojo kejo (d) ojo kinni
  2. Ba mi na omo mi ___(a) alaigboran ni (b) o ti baje ju (d) ko denu olomo
  3. Awon agbateru eto idana laye ode oni ni _______(a) baba oko (b) alaga iduro ati alaga ijoko (d) Baba iyawo
  4. Oro ile ti won maa n se fun iyawo lenu ona ile oko re lojo igbeyawo ni _____(a) ese fifo (b) orin kiko (d) owo fifo
  5. Ti obinrin ba lahun lati fe oko re ni igba akoko ni a mo si (a) Ijohen/ijohun (b) iya gbo (d) idana
  6. Igbese akoko ninu eto igbeyawo ni ____ (a) Ifojusode (b) alarina (d) itoro

Ninu aroso ati aroko ti a menu ba.

  1. Akole eko naa ni _____(a) iwe kika (b) aroso ati aroko (d) akaye
  2. Oruko oluko yii ni ____(a) ladele (b) olaiye (d) ladeebo
  3. Tani o koko dide lati soro lori oro yii (a) Bolanle (b) Tope (d) Sola
  4. _____ ni ori oro ti won ko aroko le lori (a)oja ale (b) bi mo se lo isinmi mi (d) ile-iwe mi
  5. Iseju meloo ni oluko fun won lati ko aroko yii? (a) mewa (b) ogbon (c) ogoji
  6. Odo tani Foyinsola ati Iteola lo lati lo lo isinmi olojo gboro ti o koja (a) Iya ila (b) iya egba (d) iya oyo
  7. Ilu wo ni iya ila n gbe (a) ilu oyo (b) ila orangun (d) Eko
  8. Ta ni o so itan fun awon Foyinsola ati Iteola? (a) baba won (b) iya won (d) iya ila
  9. kin ni oruko omo iya egun? (a) Bose (b) Idowu (d) titi
  10. Ta ni iya egun be wi pe ki o ba oun gba owo lowo omo oun? (a) Solomon (b) simoni (d) sidiku

IPIN KEJI

Dahun gbogbo awon ibeere wonyi.

A. Daruko awon ohun eto isomoloruko marun-un

i. __________________________________

ii. __________________________________

iii. _____________________________________

iv. _____________________________________

v. _____________________________________

B. Daruko marun-un ninu igbese ti a gbodo tele ninu eto igbeyawo ni ile Yoruba

i. __________________________________

ii. __________________________________

iii. _____________________________________

iv. _____________________________________

v. _____________________________________

D. Daruko ohun elo idana marun-un

i. __________________________________

ii. __________________________________

iii. _____________________________________

iv. _____________________________________

v. _____________________________________

E. Daruko ibi ayeye marun-un ti a ti lee ko orin ibile

i. __________________________________

ii. __________________________________

iii. _____________________________________

iv. _____________________________________

v. _____________________________________

Spread the word if you find this helpful! Click on any social media icon to share
Use the search box to search for any topics or subjects that you want
Use the search box to search for any topics or subjects that you want