YORÙBÁ JSS 2 TÁÀMÙ KËTA IGBAGBO YORUBA
ÕSÊ | ORÍ ÕRÕ/ ÀKÓÓNÚ | ÀMÚŚE IŚË |
1. | ÀŚÀ: Ìsômôlórúkô ÀKÓÓNÚ IŚË 1. Ìgbàgbö Yorùbá nípa bí orúkô śe śe pàtàkì tó (orúkô ômô ni ìjánu ômô, orúkô a máa ro ômô) orúkô rere. 2. Ètò ìsômôlórúkô b.a lílo ìrèké, oyin, àádùn, abbl (àwôn ohun èlò ìsômôlórúkô). | OLÙKÖ 1. Śe àlàyé ìgbàgbö Yorùbá nípa pàtàkì orúkô. 2. Dárúkô àwôn ohun-èlò ìsômôlórúkô bí i àádùn, orógbó, ataare, oyin abbl fún àwôn àfihàn swo èyí tí ó bá wà ní àröwötó. 3. Dari àwôn akëkõö láti śe eré ìsômôlórúkô nínú kíláásì AKËKÕÖ 1. Tëtí sí àlàyé olùkö nípa pàtàkì orúkô àti ètò ìsômôlórúkô, sì śe àkôsílê kókó kókó õrõ bí ó ti yç. 2. Sô ohun tí wön mõ nípa ìsômôlórúkô sáájú ìdánilëkõö 3. Dárúkô àwôn ohun-èlò ìsômôlórúkô pêlú dídá õkõõkan wôn mõ 4. Śe eré ìsômôlórúkô OHUN-ÈLÒ ÌKÖNI 1. Ohun èlò ìsômôlórúkô; oyin, ataare, orógbó,obì, çja, omi, ìrèké 2. Àwòrán ohun èlò ìsômôlórúkô 3. Fídíò ètò ìsômôlórúkô. |
2. | ÈDÈ: ìsõrí õrõ Õrõ aröpò orúkô àti õrõ aröpò afarajorúkô. ÀKÓÓNÚ IŚË 1. Oríkì õrõ aröpò-orúkô 2. Àbùdá õrõ aröpò-orúkô 3. Àlàyé lórí õrõ aröpò-afarajorúkô àti wúnrên rê. | OLÙKÖ 1. Fún õrõ aröpò-orúkô ní oríkì. Õrõ aröpò-orúkô ni àwôn õrõ tí a lò dípò õrõ-orúkô nínú gbólóhùn. 2.Śe àlàyé àbùdá õrõ aröpò-orúkô fún akëkõö. Bí i, ó máa ń töka sí iye (çyô àti õpõ), ó töka sí ipò (çnìkínní, kejì, këta). B.a. Mo jç êbà: çnìkínní çyô 3. Śe àlàyé lórí õrõ aröpò-afarajorúkô àti àwôn wúnrên rê fún akëkõö. (jë kí akëkõö mõ pé ó ń töka sí iye àti ipò). Wúnrên tàbí õrõ atoka rê ni; Èmi, ìwô, êyin, òun àti àwôn. AKËKÕÖ 1. Śe àdàkô àwôn gbólóhùn tí olùkö kô sójú pátákó sí inú ìwé wôn. 2. Tëtí sí àlàyé olùkö. OHUN-ÈLÒ ÌKÖNI 1. Kádíböõdù tí a kô àpççrç gbólóhùn tí a ti lo õrõ aröpò-orúkô àti õrõ aröpò-afarajorúkô sí. 2. Àwòrán àtç õrõ aröpò-orúkô àti õrõ aröpò-afarajorúkô. |
3. | ÒÝKÀ: Õödúnrún dé Êëdëgbêta (300 – 500) ÀKÓÓNÚ IŚË Òýkà láti Õödúnrún dé Êëdëgbêta (300– 500) 320 = Okòólélöõödúnrún 400 = Irínwó 460 = Õtàlénírínwó, abbl | OLÙKÖ 1. Tö akëkõö sönà láti ka òýkà Õödúnrún dé Êëdëgbêta (300 – 500). 2. Śe àlàyé ìgbésê òýkà ní kíkún. AKËKÕÖ 1. Ka òýkà láti Õödúnrún dé Êëdëgbêta (300 – 500) 2. Dá òýkà tí a kô sójú pátákó mõ ní õkõõkan. 3. kô òýkà tí olùkö kô sí ojú pátákó sínú ìwé. OHUN-ÈLÒ ÌKÖNI 1. Kádíböõdù tí a kô òýkà Õödúnrún dé Êëdëgbêta (300 – 500) sí. 2. Káàdì pélébé pélébé tí a kô òýkà kõõkan sí. |
4. | ÀŚÀ: Ìsômôlórúkô ÀKÓÓNÚ IŚË 1. Ètò ìsômôlórúkô, bí a śe ń lo àwôn ohun èlò ìsômôlórúkô bí i obì, orógbó, ataare, oyín, ìrèké abbl fún ìwúre 2. Oríśiríśi orúkô * Àbísô * Àmútõrunwá * Oríkì * Àbíkú * Ìnágijç, abbl. | OLÙKÖ 1. śe àlàyé ètò ìsômôlórúkô fún àwôn akëkõö 2. kô oríśiríśi orúkô sí ojú pátákó 3. Darí akëkõö láti śe eré ìsômôlórúkô nínú kíláásì AKËKÕÖ 1. Tëtí sí àlàyé olùkö nípa ètò ìsômôlórúkô àti bí a śe ń lo õkõõkan àwôn ohun èlò ìsômôlórúkô fún ìwúre, kí ó sì kô àwôn kókó kókó õrõ b ó ti yç 2. śe àwòkô orúkô tí ó wà lójú pátákó 3. śe eré ìsômôlórúkô OHUN-ÈLÒ ÌKÖNI 1. Ohun èlò ìsômôlórúkô bí i obì, orógbó, ataare, oyín, ìrèké, àádùn 2. Kádíböõdù tí a to orúkô ômô àti ìtöjú wôn sí. 3. Fídíò ètò ìsômôlórúkô. |
5. | ÈDÈ: Aáyan Ògbufõ (ôlörõ geere àti ewì) ÀKÓÓNÚ IŚË 1. Títúmõ àyôlò ôlörõ geere kéèkèèké ní èdè Gêësì sí èdè Yorùbá 2. Títúmõ àyôlò ôlörõ geere ní èdè Yorùbá sí èdè Gêësì. 3. Títúmõ ewì ní èdè Gêësì sí èdè Yorùbá. | OLÙKÖ 1. Tö akëkõö sönà láti túmõ àyôlò ôlörõ geere kéèkèèké ní èdè Gêësì sí èdè Yorùbá. 2. Tö akëkõö sönà láti túmõ àyôlò ôlörõ geere kéèkèèké ní èdè Yorùbá sí èdè Gêësì. 3. Tö akëkõö sönà láti túmõ ewì kúkurú ní èdè Gêësì sí èdè Yorùbá. AKËKÕÖ 1. Túmõ àyôlò ôlörõ geere kéèkèèké ní èdè Gêësì sí èdè Yorùbá. 2. Túmõ àyôlò ôlörõ geere kéèkèèké ní èdè Yorùbá sí èdè Gêësì. 3. Túmõ ewì kúkurú ní èdè Gêësì sí èdè Yorùbá. OHUN-ÈLÒ ÌKÖNI 1. Ìwé àyôkà ôlörõ geere ní èdè Gêësì sí èdè Yorùbá. 2. Ìwé àpilêkô ní èdè Gêësì àti Yorùbá 3. Pátákó ìkõwé 4. Ìwé atúmõ èdè |
6. | LÍTÍRÈŚÕ: Lítírèśõ Alohùn ÀKÓÓNÚ IŚË 1. õgangan ipò: – ìtumõ – Àbùdá rê
2. Õrõ-ìśe tí a fi gbé wôn jáde bí i pípè, sísun, kíkô, dídá, mímu abbl. | OLÙKÖ 1. Śe àlàyé pé akëkõö nílò láti ní ìmõ nípa àwôn àbùdá õgangan ipò lítírèśõ alohùn kan bí àgbéyêwò rê tó kún. 2. Śe àlàyé nípa àbùdá õgangan ipò lítírèśõ alohùn díê bí àpççrç (ìjálá, çkún ìyàwó, àlö onítàn). 3. Śe àlàyé õrõ-ìśe tí wön fi máa ń gbé àwôn ewì alohùn kan jáde. Bí àpççrç; Ìjálá – sísun, Ègè – dídá, orin – kíkô abbl AKËKÕÖ 1. Tëtí sí àlàyé olùkö 2. Śe àkôsílê kókó inú àlàyé náà 3. Béèrè ohun tí ó ná rú ô lójú 4. Śe àpççrç àbùdá õganganipo lítírèśõ alohùn mìíràn yàtõ sí èyí tí olùkö śe. OHUN-ÈLÒ ÌKÖNI 1. Fíìmù 2. Rédíò 3. Téèpù 4. Kásëêtì 5. Ìwé lítírèśõ alohùn àdàkô. |
7. | ÈDÈ: Ìsõrí – Õrõ Õrõ-Atökùn àti õrõ-àsopõ ÀKÓÓNÚ IŚË
| OLÙKÖ 1. Śe àlàyé õrõ-atökùn àti àwôn wúnrên rê fún akëkõö bí àpççrç; si, ni abbl 2. Sô ìtumõ õrõ-àsopõ fún akëkõö 3. Dárúkô àwôn wúnrên õrõ-àsopõ bí i; pêlú, òun, śùgbön, àyàfi abbl fún akëkõö. 4. Śe àlàyé bí a śe lè dá ìsõrí õrõ kõõkan mõ nínú gbólóhùn. AKËKÕÖ 1. Tëtí sí àlàyé olùkö. 2. Kô àwôn ìsõrí õrõ tí olùkö kô sí ojú pátákó sínú ìwé wôn. OHUN-ÈLÒ ÌKÖNI 1. Ìwé gírámà òde-oni 2. Ìwé Èdè-Ìperí Yorùbá 3. Kádíböõdù tí a kô àpççrç àwôn wúnrên õrõ-àsopõ àti õrõ-atökùn sí |
8. | ÀŚÀ: Ìtêsíwájú Lórí Êkö-Ilé ÀKÓÓNÚ IŚË
· Ìkíni, ìbömôwí · Ìbõwõfágbà · Ìgböràn · Níní sùúrù · Iśë inú ilé śíśe · Jíjë ômôlúàbí sí òbí àti àwùjô
· Gbígba àlàáfíà láàyè · Fífi ara çni sí ipò ômôlàkejì · Agbófinró abbl | OLÙKÖ 1. Śe àlàyé lórí ìwà ômôlúàbí àti oríśiríśi ìwà ômôlúàbí tí a lè bá löwö ômô tí ó ní êkö-ilé. 2. Śe àlàyé àwôn õnà tí a lè gbà dëkun ìwà ìkà sí ômôlàkejì láwùjô. 3. Darí ìjíròrò lórí õnà tí a lè gbà dëkun ìwà ìbàjë sí ômôlàkejì. AKËKÕÖ 1. Tëtí sí àlàyé olùkö 2. śe àfihàn ìkíni lóríśiríśi õnà, ìwà ômôlúàbí àti ìtöjú ilé. 3. Kô ohun tí olùkö kô sí ojú pátákó sí inú ìwé rç. 4. Kópa nínú ìjíròrò tí olùkö darí OHUN-ÈLÒ ÌKÖNI 1. Àwòrán 2. Fíìmù 3. Téèpù 4. Pátákó ìkõwé 5. Ìwé ìròyìn àtigbà-dé-gbà 6. Tçlifísàn/ Rédíò. |
9. | ÌBÁŚEPÕ LÁÀRIN ÈDÈ ÀTI ÀŚÀ ÀKÓÓNÚ IŚË
| OLÙKÖ 1. Śe àlàyé ìwúlò èdè fún akëkõö (jë kí akëkõö mõ pé mö-yà-mí ni èdè àti àśà jë fún àwùjô àti pé bí kò sí èdè àwùjô kò sí). 2. Śe àlàyé fún akëkõö pé bí èdè śe ń dàgbà ni ìgbélárugç ń bá àśà. 3. Jë kí akëkõö mõ pé èdè ni a fi ń sõrõ tí a fi ń gbé èrò inú çni jáde. AKËKÕÖ 1. Tëtí sí àlàyé olùkö 2. Kô ohun tí olùkö kô sí ojú pátákó sí inú ìwé rç. OHUN-ÈLÒ ÌKÖNI 1. Pátákó ìkõwé 2. Àwòrán tí ó śe àfihàn àśà ìgbéyàwó tàbí ìsômôlórúkô. |
10. | ÀŚÀ: Oge Śíśe ÀKÓÓNÚ IŚË 1. Pàtàkì oge sis 2. Oríśiríśi õnà tí a ń gbà śoge Ayé àtijö;
3. Oge śíśe lóde òní;
| OLÙKÖ 1. Tö akëkõö sönà nípa ìdí tí àwôn Yorùbá fi máa ń śoge. 2. Śe àfihàn ohun èlò oge śíśe 3. Tö akëkõö sönà láti dárúkô irúfë oge śíśe tí ó wà ní òde òní àti àléébù tí ó wà níbê fún ôkùnrin àti obìnrin. AKËKÕÖ 1. Sô ohun tí o śàkíyèsí nípa oge śíśe ní àwùjô àti ìdí pàtàkì tí àwôn ènìyàn fi ń śe oge. 2. Sô irúfë oge śíśe tí wön mõ mô obìnrin sáájú ìdánilëkõö. OHUN-ÈLÒ ÌKÖNI 1. Ohun èlò gidi bí i; tìróò, làálì, bèbè-ìdí, ìlêkê, osùn,wíìgì, lëêdì, èékánná abbl 2. Àwòrán oríśiríśi irun dídì, irun gígé abbl 3. Àwòrán tí ó śe àfihàn àwôn ilà ojú tí àwôn Yorùbá máa ń kô. |
11. | ÈDÈ: Ìsõrí Õrõ Õrõ-àpönlé àti õrõ-àpèjúwe ÀKÓÓNÚ IŚË
| OLÙKÖ 1. Sô oríkì tàbí ìtumõ õrõ-àpönlé fún akëkõö, kí o sì fi àpççrç rê han nínú gbólóhùn. Bí àpççrç: Igi náà ga fíofío. 2. Śe àlàyé iśë tí õrõ-àpèjúwe ń śe nínú gbólóhùn fún akëkõö. B.a. Aśô pupa ni Böla wõ AKËKÕÖ 1. Tëtí sí àlàyé olùkö 2. Kô àwôn ìsõrí õrõ tí olùkö kô sí ojú pátákó sínú ìwé. 3. Śe àpççrç àwôn gbólóhùn mìíràn tí ó ní õrõ-àpönlé àti õrõ-àpèjúwe yàtõ sí èyí tí olùkö kô. OHUN-ÈLÒ ÌKÖNI 1. Ìwé gírámà òde òní 2. pátákó ìkõwé Káàdì pélébé pélébé tí a kô õrõ-àpönlé àti õrõ àpèjúwe sí. |
12. | ÀTÚNYÊWÒ ÊKÖ | |
13. | ÌDÁNWÒ |