ÕSÊ ORÍ ÕRÕ/ ÀKÓÓNÚ ÀMÚŚE IŚË 1. ÀŚÀ: Ìsômôlórúkô ÀKÓÓNÚ IŚË 1. Ìgbàgbö Yorùbá nípa bí orúkô śe śe pàtàkì tó (orúkô ômô ni ìjánu ômô, orúkô a máa ro ômô) orúkô rere. 2. Ètò ìsômôlórúkô b.a lílo ìrèké, oyin, àádùn, abbl (àwôn ohun èlò ìsômôlórúkô). OLÙKÖ 1. Śe àlàyé ìgbàgbö Yorùbá nípa pàtàkì orúkô.
Subject : Yoruba Class : Jss 2 Term : Second Term Week : Week 2 Topic : EDE: Aroso Alapejuwe (ilana bi a se le ko aroko Yoruba ) ASA: Asa Iranra Eni lowo- Ajo, Esusu, Egbe Alafowosowopo LIT: Litireso Alohun to je mo Esin Ibile- Iyere Ifa, Iwi, Ijala Iremoje.
Edu Delight Tutors Subuode Gbaga Gasline Ogun State 1st Term Examination YORUBA JSS 1 IPIN A DAHUN GBOGBO IBEERE NI IPIN YII ————– ni baba n la awon Yoruba (a) Odudua (b) Orunmila (d) Obatala Nibo ni awon Yoruba ti se wa? (a) Oyo (b) meta (d) ile ife Ojo melo ni Oduduwa fi rin
YORUBA LANGUAGE SCHEME OF WORK JSS 1 SAA ETO ISE FUN SAA KIN-IN-NI YORUBA LANGUAGE SCHEME OF WORK JSS 1 SAA ETO ISE FUN SAA KIN-IN-NI Alifabeeti ede Yoruba Itan isedale Yoruba Oriki litireso Ami ohun lori awon faweeli ati oro onisilebu kan Ile-ife saaju dide oduduwa Ami ohun Awon eya Yoruba
OSE KOKANLA EKA ISE: EDE AKOLE ISE: ISORI ORO NINU GBOLOHUN Isori oro ni abala ti a pin awon oro inu ede yoruba si. Isori oro Yoruba oro-oruko (NOUN) oro-aropo oruko (PRONOUN) oro ise (VERB) oro Aropo afarajoruko (PROMINAL ) oro apejuwe ( ADJECTIVE ) oro atoku (PREPOSITION) oro asopo ( CONJUCTION ) EKA
OSE KEWAA EKA ISE: EDE AKOLE ISE: AROKO ATONISONA ALAPEJUWE. Aroko je ohun ti a ro ti a sise akosile. Aroko alapejuwe ni aroko ti o man sapejuwe eniyan, ibikan ati nnkan to n sele gege bi a se ri i gan-an. Apeere: Oja ilu mi Egbon mi Ile-iwe mi Ouje ti mo feran Ilu
OSE KESA-AN EKA ISE: EDE AKOLE ISE: ORIKI ATI ILANA KIKO AROKO YORUBA PELU APEERE. Aroko je ohun ti a ro ti a si se akosile re lori pepa ILANA FUN KIKO AROKO yiyan Ori-oro: A ni lati fa ila teere si abe ori-oro ti a n ko aroko le lori sise ilapa ero: A
OSE KEJO EKA ISE: EDE AKOLE ISE: OSE KEJO EKA ISE: EDE AKOLE ISE: ONKA – OOKALELAADOTA DE OGORUN-UN (51-100). 51 Ookan le laadota 50+1=51 52 Eeji le laadota 50+2=52 53 Eeta le laadota 50+3=53 54 Eerin le laadota 50+4=54 55 Aarun din logota 60-5=55 56 Eerin din logota 60-4=56 57 Eeta din logota 60-3=57
OSE KEJE EKA ISE: EDE AKOLE ISE: ONKA YORUBA LATI OOKAN DE AADOTA (1-50). Onka Yoruba je ona ti a n gba lati ka nnkan ni ona ti yoo rorun. Nonba 1 Ookan 2 Eeji 3 Eeta 4 Eerin 5 Aarun-un 6 Eefa 7 Eeje 8 Eejo 9 Eesan-an 10 Eewaa 11 Ookanla 10+1=11 12
OSE KEFA EKA ISE: EDE AKOLE ISE: AKOTO AWON ORO TI A SUNKI Akoto ni sipeli titun ti awon onimo ede Yoruba fi enu ko le lori ni odun 1974 lati maa lo. Sipeli atijo Sipelu titun Olopa Olopaa Na Naa Orun Oorun Ogun Oogun Anu Aanu Papa Paapaa Suru Suusu Alafia Alaafia Oloto Oloooto