Second Term Revision and Readiness Test Yoruba Primary 3 Second Term Lesson Notes Week 1
Oruko: ……………………………………………………….……… Deeti: …………………….
Ise: Ede Yoruba
Kilasi: Oniwe Keta
Isoro n gbesi ni ile aro
- Ojo ti awon omode lo be ile aro wo je ojo ……………… (a) Abameta (b) Eti (d) Aiku
- …………………. Ni ohun ti awon alagbede fi maa n finna. (a) Ewiri (b) Omo owu
- Kini oruko ti a n pe irnse ti alagbe fii n mu irin ninu ina? (a) amuga (b) emu
(d) reeki
- Bawo ni a se maa n ki alagbede? (a) aroye o (b) aredu o (d) e mo o se o
- Kini oruko ibi ise alagbede? (a) ile aro (b) ile ita (d) ile oja
Onka ni ede Yoruba
- Kini oruko nomba yii ni ede Yoruba – 25? (a) aarundinlogbo (b)aarundinlogoji (d) aarundinlogun
- Kini oruko nomba yii ni ede Yoruba – 40? (a) ogbon (b) ogoji (d) aadota
- Kini oruko nomba yii ni ede Yoruba – 15? (a) aarudinlogun (b) aarundinlogoji (d) ogun
- Kini oruko nomba yii ni ede Yoruba – 20? (a) ogbon (b) ogoji (d) ogun
- Kini oruko nomba yii ni ede Yoruba – 35? (a) aarudinladota(b) aarundinlogoji (d) aarundinlogun
Kika ati kiko gbolohun kekeeke:
- ……………………….ni o n di irun (a) Sola (b) Peju (d) Yemi
- …………………………ni o n foe yin (a) Kemi (b) Tayo (d) Sade
- ……………………………….ni o wo kaba (a) Gbemi (b) Bisi (d) Tayo
- ………………………..ni o n foe se (a) Gbemi (b) Sola (d) Wunmi
- ………………………….ni o n je eko (a) Peju (b) Bisi (d) Wunmi
Daruko nkan marun-un ti o wa ni inu ilu.
- …………………………………………………………..
- …………………………………………………………..
- ……………………………………………………………
- ……………………………………………………………
- ……………………………………………………………