THIRD TERM PROMOTIONAL EXAMINATION
CLASS: PRIMARY 3
SUBJECT: YORUBA LANGUAGE
NAME:……………………………………………………………………………………
ASA IKINI
- Nibo ni Alake ba iya re lo? (a) si odo iyasola (b) si odo iya tunde
- Kiini iya sola sese se? (a) osese lo si ile iwosan (b) osese bimo
- Bawo ni a sen ki eni ti o ba sese bimo? (a) Eku ise o (b) Eku ewu omo
- Bawo ni a se nki eni ti o nsile? (a) ile a tura o (b) eku inawo
- Bawo ni a se nki alagbede? (a) emo se o (b) aro ye o
Owe Ile Yoruba
- Pari owe yii: Agba kii nwa loja, _______________ (a) kori omo tuntun wo (b) ki inu obi ni
- Pari owe yii: Bi omode ba mo owo we, ____________ (a) Owo e a mo ni (b) A ba agba jeun
- Pari owe yii: Ile ti a fi ito mo, ____________ (a) irin ni yoo wo (b) ategun a gbe lo
- Pari owe yii:: Eni ti yoo je oyin inu apata, __________ (a) aake aro ni (b) kii now enu aake
- Pari owe yii: Bami na omo mi __________ (a) (a) owo dun iya e ni (b) ko de inu olomo
Ipolowo Oja
- Oja wo ni a npolowo bayii: langbe jinna o , oroku ori ebe (a) orisu sise (b) alagbado
- Oja wo ni a npolowo bayii: gbetuuru o, omi akerese, kii ndun lodo, to ba dele, adoyin
(a) eleja tutu (b) eleran
- Oja wo ni a npolowo bayii: lamuruke ___sokudale adalu (a) onisu sise (b)elewa sise
- Oja wo ni a npolowo bayii: gbanjo, gbanjo, ko lo nle, ko dowo o, oyinbo wo gbese oko mi lo nse emi ni mo nta (a) alaso (b) gaari
- Oja wo ni a npolowo bayii: ______ re one re, ewoju ob eke mu ______ (a) Asaro (b)Iyan
ALO APAMO
- Aloo, aalo, kilo koja niwaju oba ti ko ki oba, kii nio, (a) Esinsin (b) Agbara oko
- Aloo, aalo opo baba alo kan lae lae opo baba alo kan laelae, ojo to ba de fila pupa, ni iku de ba kiinio (a) sigidi (b) abela / siga
- Aloo, aalo, ile gbajumo kiki imiera, kiini o: (a) osan (b) ibepe
- Aloo, aalo, okun nho yaya, osa nho yaya, omo buuruku to rib o, kiini o: (a) Omorugun (b) irin
- Aloo, aalo, gele dudu gbaje ona kiini o: (a) eera (b) ijalo
About The Author

Edu Delight Tutors
Am a dedicated educator with a passion for learning and a keen interest in technology. I believe that technology can revolutionize education and am committed to creating an online hub of knowledge, inspiration, and growth for both educators and students. Welcome to Edu Delight Tutors, where learning knows no boundaries.