CLASS BASIC 2 YORUBA 2ND TERM EXAMS

2ND TERM EXAMINATION

SESSION: .

CLASS: BASIC 2

SUBJECT: YORUBA

 

Fa ila si idahun ti oye

 

1. Daruko orisirisi irun didi meta laye atijo __________ __________ __________

2. Daruko iru didi lode meta lode oni __________ __________ __________

3. Ewo ninu wonyi ni kin se ohun elo idiri (a) Ooya (b) Iyaruun (d) gege

4. Bawo lase nki onidiri laye atijo (a) Oju gboro (b) Mo kota (d) Mokope

5. Ewo ni ki se oruko iru didi? (a) kolese (b) Larondo (d) Ipako Elede

6. Se omo odun mewa ni eto lati dibo? (a) Beeni (b) Beeko (d) boya

7. Se gbogbo eniyan lo ni eto lati kawe? (a) beeni (b) Beeko (d) mi ko mo

8. _____ ko ni eto lati wa oko (a) olowo (b) Afoju (d) Agbejoro

9. _____ je oro-ise (a) Jeun (b) Ewure (d) Tabili

10.  Or-ise ma nfi _____han ninu gbolohun (a) Itumo (b) Ohun ti o sele (d) Oruko