YORUBA 1st term Examination Primary 2

 

CLASS: BASIC 2

SUBJECT: Yoruba

Pin awon oro wonyi si silebu

  1. Eleran
  2. adesola
  3. Omode
  4. Koroba
  5. Silebu AKAYE

Edu Delight Tutors

1st TERM EXAMINATION

Jide je omo onipanle ati alaigboran. Kii f’eti sile si ohun ti awon obi re ba n so. Opo igba

ni yio kuro nile ti ko si ni lo si ile-iwe. Ojo ti o ba si jaja lo si ile- iwe, ko ni teti si ohun ti oluko re n hoo o feran lati ma sere pupo, ko ni ero miran ju ki o sere, ki o si jeun. Nigbati o di akoko Idanwo ni ile eko , ko kawe ere ni o se kiri. Nigbati o fidiremi leyi ti awon egbe re ti o foju s’eko yege ninu idanwo

IBEERE

  1. Tani omo onipanle?
    1. Bola (b) Dele (d) Dide
  2. Nibo ni o ye ko lo ti oba kuro nile?
    1. Ile ijosin (b) ile-ofin (d) ile-iwe
  3. kin-ni jide feran lati ma a se?
    1. Ere
    2. Jale

(d) Sokun

  1. Akoko wo ni ko kawe?
    1. Akoko ebi
    2. Akoko idanwo

(d) N ko mo

  1. Kin-ni o sele si I ni igbeyin?
    1. O yege
    2. O fidi remi

(d) O di olowo THEORY

  1. Ko oro oruko Meta

FA’LA SI ORO ORUKO to’wa ninu awon gbolohun

  1. Dele ra moto titun
  2. Ibadan ni gbogbo wa n gbe
  3. Mo n fo aso ati gele