Bi ase nki onise owo ati bi won se nda wo lohun

Pry two

Akole:Asa ikini ni ile yoruba

Orisirisi ona ni awa yoruba ngba ki ara wa ninu asa ikini ati lati mo omo yoruba lawujo.awon ona naa ni awon wonyi::

1 ikini ni asiko

2 ikini ni igba

3 ikini si ipo ti aba wa tabi ohun tio ba sele sii eniyan

4 ikini ni enu ise ati bi won se dahun

5 kiki oba ati ijoye gege bi ipo won

IKINI NI ASIKO

ni dede agogo meje owuro si agogo mokanla abo(11:30) ekaaro o pelu ido bale ati ikunle ni fun omokunrin ati omobinrin
Ni dede agogo mejila osan si agogo meta abo e kaasan o

Ni dede agogo merin irole si agogo mefa abo ni e ku irole o

Ni dede agogo meje ale si agogo mokanla abo e kaale o

Ni asiko ti aba fe sun o daaro ki olorun ji wa re o kamaa toju orun de iju iku oo layo ni a o ji o
2
Bi ase nki onise owo ati bi won se nda wo lohun

Ise kilaasi
1.Bawo ni omo okunrin se nki baba tabi iya re?(a)idobale (b)ikunle.

2.Bawo ni omo obinrin se nki baba tabi iya re?(a)ikunle. (b)idobale

3.A maa nki ara wa nibowuro ni dede agogo bayii?(a)meje si mokanla abo (b)mejila si meta abo,

Spread the word if you find this helpful! Click on any social media icon to share

Add a Comment

Your email address will not be published. Required fields are marked *