Yoruba

Awọn Orukọ Amu Torun Wá Ní Ilé Yoruba

  Class: Pry Six   Subject: Yoruba Studies   Akole:Awon omo amutorunwa   Awon omo wo ni ape ni omo amutorunwa?Omo amutorunwa ni awon omo ti a bi ni ipase ami iyanu ona ti won gba waye yato si bi a ti bi omo orisirisi ona ni won gba waye. Awon omo amutorunwa naa ni

OWE ILE YORUBA (Pry 6)

Pry six Akole: OWE ILE YORUBA   Eni ti yoo je oyin inu apata,koni wo enu aake   Oju ti yoo baa ni kale, kin ti owuro sepin   ile ti afi to omo,iri ni yoo wo   kekere la ti npeka iroko,toba dagba tan apa kii nka   Bi omode mo owo we,aba agba

OGE SISE NI ILE YORUBA

  Class: Pry six Subject: Yoruba Studies Akole: OGE SISE NI ILE YORUBA   Orisi risi ona ni angba se oge ni ile Yoruba, oge sise ni aye atijo ati oge sise ni aye ode oni   OGE SISE NI AYE ATIJO Awon ona wonyii ni a ngba se oge ni ile yoruba ni aye

Asa ikini ni ile yoruba

Date: Friday, 1st May, 2020. Class: Pry six Subject: Yoruba Studies   Akole: Asa ikini ni ile yoruba Orisirisi ona ni awa yoruba ngba ki ara wa ninu asa ikini ati lati mo omo yoruba lawujo. Awon ona naa ni awon wonyii:   1.) ikini ni asiko 2.) ikini ni igba 3.) ikini si ipo

Alifabeeti Èdè Yorùbá Primary 3

Àwọn wọ̀nyí ni leta tí ó wà nínú èdè alifabeeti Èdè Yorùbá À B D E Ẹ F G GB H I J K L M Ń Ó Ọ P R S Ṣ T U W Y Gbogbo leta tí ó wàá nínú èdè alifabeeti Èdè Yorùbá jé marundin lọ gbon   Àwọn alifabeeti Èdè

Yoruba Examination Second Term Basic 6

Yoruba five Koa won gbolohun wonyi sile ki o fala si idi oro – ise ti o wa ninu won. Aja ojo gbe egungun eran. Bola je eba. Oluko n ka iwe. Akekoo n pa ariwo. Sade n fo aso ile – iwe re.[mediator_tech] Ewo ni eroja idana ninu awon nnkan wony Okuta , Iyo

YORUBA LANGUAGE PRIMARY 6

PRIMARY 6 SUBJECT: YORUBA LANGUAGE NAME:…………………………………………………………………………………… IWE KIKA: DAUDA JALE AGBON 1.)Omo melo ni baba Dauda bi? (a) meji (b) meta (d) okan (e) merin 2.)Kini ise awon omo wonyii (a) agbe (b) ode (d) ademu (e) akekoo 3.)Eranko wo ni a kii je, ti Dauda maa npa (a) Eye (b) Emo (d) Adan (e)

PRIMARY 6 YORUBA LANGUAGE

NAME:…………………………………………………………………………………… IWE KIKA: DAUDA JALE AGBON        Omo melo ni baba Dauda bi? (a) meji            (b) meta         (d) okan         (e) merin    Kini ise awon omo wonyii (a) agbe     (b) ode          (d) ademu      (e) akekoo  Eranko wo ni a kii je, ti Dauda maa npa (a) Eye      

Èdè Yorùbá : Àṣà Ìran ra ẹni lowo ni ile Yorùbá

Àwọn ọ̀nà wonyi ni àwọn Yoruba má ń gba láti rán ara wọn lowo ni igba ìwáṣẹ̀   Asa Iranra Eni lowo- Ajo, Esusu, Egbe Alafowosowopo 1. Ọwẹ̀ : eleyi tún mo sì ìṣe ọkọ tí a má bàa ara wa see 2. Àárọ̀ 3. Àjò didia 4. Esùsú 5. Àrọko dodo 6. San die