Date: Friday, 1st May, 2020. Class: Pry six Subject: Yoruba Studies Akole: Asa ikini ni ile yoruba Orisirisi ona ni awa yoruba ngba ki ara wa ninu asa ikini ati lati mo omo yoruba lawujo. Awon ona naa ni awon wonyii: 1.) ikini ni asiko 2.) ikini ni igba 3.) ikini si ipo
Àwọn wọ̀nyí ni leta tí ó wà nínú èdè alifabeeti Èdè Yorùbá À B D E Ẹ F G GB H I J K L M Ń Ó Ọ P R S Ṣ T U W Y Gbogbo leta tí ó wàá nínú èdè alifabeeti Èdè Yorùbá jé marundin lọ gbon Àwọn alifabeeti Èdè
Yoruba five Koa won gbolohun wonyi sile ki o fala si idi oro – ise ti o wa ninu won. Aja ojo gbe egungun eran. Bola je eba. Oluko n ka iwe. Akekoo n pa ariwo. Sade n fo aso ile – iwe re.[mediator_tech] Ewo ni eroja idana ninu awon nnkan wony Okuta , Iyo
PRIMARY 6 SUBJECT: YORUBA LANGUAGE NAME:…………………………………………………………………………………… IWE KIKA: DAUDA JALE AGBON 1.)Omo melo ni baba Dauda bi? (a) meji (b) meta (d) okan (e) merin 2.)Kini ise awon omo wonyii (a) agbe (b) ode (d) ademu (e) akekoo 3.)Eranko wo ni a kii je, ti Dauda maa npa (a) Eye (b) Emo (d) Adan (e)
NAME:…………………………………………………………………………………… IWE KIKA: DAUDA JALE AGBON Omo melo ni baba Dauda bi? (a) meji (b) meta (d) okan (e) merin Kini ise awon omo wonyii (a) agbe (b) ode (d) ademu (e) akekoo Eranko wo ni a kii je, ti Dauda maa npa (a) Eye
Àwọn ọ̀nà wonyi ni àwọn Yoruba má ń gba láti rán ara wọn lowo ni igba ìwáṣẹ̀ Asa Iranra Eni lowo- Ajo, Esusu, Egbe Alafowosowopo 1. Ọwẹ̀ : eleyi tún mo sì ìṣe ọkọ tí a má bàa ara wa see 2. Àárọ̀ 3. Àjò didia 4. Esùsú 5. Àrọko dodo 6. San die