Yoruba Primary 4 First Term Lesson Notes Week 11 Subject: Yoruba Class: Primary 4 Term: First Term Week: 11 Age: 9 years Topic: Atunyewo Eko Lori Ise Saa Kin In Ni Sub-topic: Atunyewo Eko Lori Ise Saa; Litireso: Atunyewo Eko Lori Ise Saa Duration: 1 hour Behavioural Objectives By the end of the lesson, pupils
Yoruba Primary 4 First Term Lesson Notes Week 12 Subject: Yoruba Class: Primary 4 Term: First Term Week: 12 Age: 9 years Topic: Idanwo Ipari Saa Kin In Ni Sub-topic: Final Assessment and Review Duration: 1 hour Behavioural Objectives By the end of the lesson, pupils should be able to: Demonstrate their understanding of Yoruba
THIRD TERM SUBJECT: YORUBA CLASS: KILAASI KERIN Dahun gbogbo awon ibeere wonyi Oriki orile yato si oriki ilu (a) beeko (b) beeni (d) n ko mo Kini ogota ni nomba (a) 50 (b) 70
NAME:…………………………………………………………………………………… ORIKI ILU Ilu wo ni a nki bayii pe, mesi ogo, nile oluyole, nibi ole gbe njare onihun (a) Ibadan (b) Akura (d) Oyo Ilu wo ni a nki bayi pe, akete ile ogbon, aromisa legbe legbe (a) Egba (b) Eko (d) Akure ) Ilu wo ni a nki bayi pe:
Edu Delight Tutors LAGOS SECOND TERM EXAM BASIC 4 1. Ewo ni ki se elo idana ni ile yoruba (a) Epo pupo (b) isu (c) ewa 2. Oko ati iyawo maa n wo aso __________ ninu igbeyawo (a) Igbalode (b) ibile (c) idoti 3. Ewo ni kii nse orisi owe ni ile Yoruba? (a) Owe
Pry four Ose kinni Akole:onka ni ede Yoruba lati ori aarun de ori ogorun(5-100) 5-Aaron 10-Eewa 15-Aarundinlogun 21-16-Erindinlogun 17-Etadinlogun 18-Ejidinlogun 19-okandinlogun 20-Ogun 21-Okanlelogun 22-Ejilelogun 23-Etalelogun 24-Erinlelogun 25-Arundinlogbon 26-Erindinlogbon 27-Etadinlogbon 28-Ejidinlogbon 29-Okandinlogbon 30-Ogbon 31-okanlelogbon 32-ejilelogbon 33-etalelogbon 34-erinlelogbon 35-Aarundinlogoji 36-erindinlogoji 37-etadinlogoji 38-ejidinlogoji 39-okandinlogoji 40-Ogoji Ise kilaasi Kinni oruko awon nomba wonyii ni ede yoruba 1.32