OSE KARUN-UN EKA ISEl LITIRESO AKOLE ISE: Akoto ode-oni Akoto ni ona ti a n gba ko ede Yoruba ni ona ti o bojumu ju ti ateyinwa lo. Alaye lori akoto ode-oni Ede Yoruba di kiko sile ni odun 1842 Pelu iranlowo awon ajihinrere ijo siemesi bisobu Samueli Ajayi crowther ati Henry Townsend. Ile ijosin
OSE KERIN EKA ISE: EDE AKOLE ISE: SILEBU Silebu ni ege oro ti o kere julo ti eemi le gbe jade leekan soso lai si idiwo. Iye ami ohun ti o jeyo ninu oro kan ni iye silebu iru oro bee. Ihun oro orusilebu kan le je, I faweli nikan –(F) ii Apapo konsonati ati
OSE KETA Eka Ise Ede Akole Ise Ede Ami Ohun lori oro onisilebu meji i ba – ta(shoe) (dd) – kf – kf ii E – we(leaf) (rd) – f – kf iii A– ja(dog) (rm) – f – kf iv Ba – ba (father)(dm) – kf – kf v Ti – ti(a name of
OSE KEJI EKA ISE EDE AKOLE ISE Ami Ohun lori awon faweli ati oro onisilebu kan. Ami ohun ni o maa n fi iyato han laarin iro kan si iro keji. Ohun Isale \ (d) o doju ko opa osi Ohun aarin – (r) O wa ni ibu Ohun Oke / (m) O doju ko
AKOLE ISE – ALIFABETI YORUBA ALIFABEETI JE AKOJOPO LETA TI ASE AKOSILE RE GEGE BI IRO NINU EDE YORUBA. ALIFABETI EDE YORUBA Aa Bb Dd Ee Ee Ff Gg GB gb Hh Ii Jj Kk Ll Mm Nn Oo Oo Pp Rr Ss Ss Tt Uu Ww Yy Apapo alifabeti ede Yoruba je meedogun (25)
Subject : Yoruba Class : Jss 2 Term : Third Term Week : Week 9 Previous Topics : 1 Atunyewo ise saa keji. 2 EDE Leta gbefe. Ohun ti leta gbefe je, awon ona ti a le gba ko leta gbefe (deeti, ikini, Ipari). ASA Igbagbo awon Yoruba nipa
Subject : Yoruba Class : Jss 2 Term : Third Term Week : Week 8 Topic : EDE Ami Ohun Oro Onisilebu Meji. ASA Awon Eya Yoruba ati ibi ti won tedo si. LIT Kikai we Apileko ti Ijoba yan. OSE KEJO EDE
Subject : Yoruba Class : Jss 2 Term : Third Term Week : Week 7 Topic : EDE Leta aigbefe (1) ohun ti leta aigbefe je (2) awon ilana ti a le gba ko le ta aigbefe-adireesi, deeti,adireesi agbaleta,ikini ibere,koko leta, ipari. ASA Awon ohun mimo ninu esin ibile- igba
Subject : Yoruba Class : Jss 2 Term : Third Term Week : Week 6 Topic : OSE KEFA EDE LETA AIGBEFE Akoonu: Leta aigbefe Igbese kiko leta aigbefe Leta aigbefe je leta ti ko gbefe rara, ti a n ko si eni ti o wa ni ipo tabi
Subject : Yoruba Class : Jss 2 Term : Third Term Week : Week 5 Topic : OSE KARUN-UN EDE ISEDA ORO ORUKO APETUNPE (a) Igba, asiko ati onka ni awon oro oruko ti a n seda bayii maa n ba lo ju. Apeere:- Osu + osu = osoosun Odun