Di awon alafo wonyii pelu awon leta ti o ye

FIRST TERM EXAMINATION 2022/2023

CLASS: PRIMARY 1                       

SUBJECT: YORUBA

   

NAME:…………………………………………

 

  1. Di awon alafo wonyii pelu awon leta ti o ye:

A   _______ D _____ E _____ G _____ I ______ J  _____ L  ____ N  _____ O  _____ R _____ S

 

  1. Kiini oruko nomba wonyii ni ede Yoruba : 
  1. 3        (a) Eeta     (b) Arun-un
  2. 1        (a) Eerin     (b) Ookan
  3. 5        (a) Arun-un     (b) Eeji
  4. 2        (a) Eeji        (b) eefa 
  5. 4        (a) Eejo        (b)Eerin

 

  1. Kiini oruko awon aworan wonyii:
  1.     =    (a) Ile     (b) Ogba

 

  1.         =    (a) Owo,     (b)  Ese

 

  1.                               =    (a) Oju        (b) Eti

Ss

 

  1.                         =    (a)Ododo    (b) Ewe

 

  1.               =    (a) Igo         (b) Agba

       

 

  1. Di awon oro wonyii pely leta ti o ye:
  1. IL___            (a) E    (b) K
  2. OW___        (a) P    (b) O
  3. OJ____        (a) K    (b) U
  4. EW____        (a) E    (b) T
  5. IG___            (a) M    (b) O

 

FIRST TERM EXAMINATION 2022/2023

CLASS: PRIMARY 2                        SUBJECT: YORUBA

   

NAME:………………………………………………………………………………

  1. ORIN AKOMONIWA: OMO RERE 
  1. Omo rere kii ___________    (a) puro    (b) soro
  2. Omo rere kii ___________    (a) korin    (b) jale
  3. Omo rere kii ___________    (a) seke    (b) kawe
  4. Omo rere kii ___________    (a) kole    (b) ja
  5. Omo rere kii ___________    (a) sole    (b) sun

 

  1. IWA OMOLUABI: ITOJU ATI OORE SISE
  1. _______________ nse baba Aina (a) Aisan     (b) Aarun
  2. _________________ wa kii. (a) Sola    (b) Aina
  3. __________________ baba Aina nya die die (a) ese  (b) Ara
  4. ___________________ su pupo (a) omi    (b) ojo
  5. Iya _________________________ sa awon aso re si ita (a) Ade (b) Kemi
  1. IROYIN ATI ASOGBA
  1. Ile-eko mi dara: talo nsoro yii?     (a) Tunde     (b) Alaba
  2. Bee ni, sugbon ko dara to ile-eko tiwa: talo lo nsoro yii? (a) Alaba    

(b) Tunde

  1. Wo o bi ododo se po yi kilaasi mi ka: talo nsoro yii? (a) Alaba     (b) Tunde
  2. Igi ti o olew po ni ile eko temiju tire lo: talo nsoro yii? (a) Tunde    

(b) Alaba 

  1. Wo maluu ti baba mi ra, talo nsoro yii? (a) Alaba     (b) Tunde
  1. AROFO IMOTOTO
  1. Fo ______________ re bi o baji (a) eyin     (b) ese 
  2. Gba __________________ re pelu (a) inu  (b) ayika 
  3. Ge _______________ re lasiko to ye (a) irun    (b) imu
  4. Ge _______________ re to gun sobolo (a) eekanna   (b) ori
  5. ______________ ti ngbe abe eekannaa ko kere  (a) Aisan    (b) Arun

 

FIRST TERM EXAMINATION 2022/2023

CLASS: PRIMARY 3                        SUBJECT: YORUBA

   

NAME:………………………………………………………………………………

  1. EWI: IBAWI 

E dake je je je

Omo ile eko, e gbohun enun mi,

E je nkorin ara si yin leti

Bee romo ile eko 

Ti  nsojika 

Ti  nwarun-un ki 

 

  1. Arofo yii nba omo ________________ wi   (a) omo ile-eko     (b) omo ile-ise 
  2. __________ to gbo baawi ni deni _________ leyin ola (a) aya lile     (b) omo giga
  3. Omo to gbo ____________ nii fi __________ sese rin  (a) aye keke   (b) ibawi moto
  4. Eko ndi _______________ fomo to gbo ibawi  (a) iyan    (b) deko   
  5. Ero ____________ ni gbogbo omo ti nko ibawi (a) eyin lawujo     (b) iwaju nita

 

  1. HUWA IMOORE SI OBI RE

Adan dori kodo

O nwose  eye

Eje ka ronu wo

Ka mo baye tin lo

Ka mohun ti nsele nile, loko ati

Nibi gbogbo

 

  1. ____________________ dori kodo (a) Adan    (b) Owiwi
  2. O nwose ___________________ (a) Eran    (b) Eye
  3. E toju awon __________________ (a) ilu     (b) obi
  4. Eyin _________________ gbogbo (a) omode     (b) agba
  5. ___________ roko olowo  (a) egbon  (b) baba

 

  1. ITOJU ARA
  1. Ojoojumo ni _________ foe yin re (a) Ade    (b) Kola
  2. A we gbogbo _________ re das aka  (a) ese    (b) ara
  3. ___________ re a mo nini ni gbogbo igba  (a) aso    (b) irun
  4. Ma __________ rira laaye  (a) gbese     (b) gbeyin
  5. ____________ ara a maa faisan  (a) eeri     (b) irun

 

  1. ITOJU ILE
  1. Ayika ile to doti maa nfa _______ (a) aisan  (b) efori
  2. ________ kii se  ore eniyan  (a) arun  (b) obun
  3. Ka maa gba ______ laaye (a) gbegbin   (b) oorun
  4. ___________ nii wo aso _______ (a) omi igi    (b) ina onida
  5. _________ lo yeni (a) obun  (b) imototo

 

FIRST TERM EXAMINATION 2022/2023

CLASS: PRIMARY 4                        SUBJECT: YORUBA

   

NAME:………………………………………………………………………………

 

  1. IWE KIKA: ASIMU OLE
    1. _________ ni oruko oja ilu pokii    (a) ikilo     (b) oroorun       (d) ayelu
    2. Ohun ti o se akoba fun pokii ni pe.

(a) o nra epa je  (b) o ni ore pupo    (d) o nlo si oja ayelu

  1. Eni ti o bu Pokii pe “Lanboroki, oju re jaa na” ni __________ 

(a)    Ore Pokii kan    (b) obi pokii    (d) Aladugbo Pokii kan    

  1. _______________ ni eni ti won fa omo ti o jale gan-an fun lati da seria fun-un 

(a) olopaa         (b) ore Pokii     (d) ara oja ayelu 

  1. Kini oruko Aladugbo Pokii ti omu-un pada sile?  (a) Adigun (b) Alao  (d) Akanni

 

  1. IWE KIKA: ADUBI ATI IYA RE 
  1. Omo melo ni Iya Adubi bi? (a) omo meta  (b) omo merin (d) omo kan  
  2. Iru  owo wo ni Awele nse (a) o nta eja     (b) o nta isu     (d) o nta ounje  
  3. Ona wo ni Olorun gba pon Adunbi le?     (a) Adubi ba iya re ta eja (b) Adubi gbe odo oyinbo oniwaasu  (d) Adubi lo yunifasiti Ibadan
  4. Kiini o gbe Adubi de odo oyinbo oniwaasu 

(a) O fe kawe sii  (b) ko mo eniyan kankan (d) Ise omo odo

  1. Kini koje ki Awele le paaro aso bi awon elegbe re 

(a) Ko feran oge     (b) Aso won ni ilu won    (d) Ere oja re ko po  

 

  1. ILU ILE YORUBA 
    1. ___________ lo ni ilu bata  (a) onisango    (b) olobatala 
    2. Awon ____________ lo ni ilu ipese  (a) ologun   (b)  Babalawo
    3. Awon ___________ lo ni ilu Agere (a) Elegun    (b) ologun  
    4. Awon ____________ lo ni ilu igbin (a) olobatala     (b) elegun  
    5. Awon ___________ lo ni ilu gbedu (a) olosa     (b) oba ati ijoye

 

  1. OJU KO KURO
    1. Ohun to nfa oku kokoro ni ______ (a)  iwa ibaje (b) afowofa  (d) aini-itelorun
    2. Ohun ti o nbere ole ni ________ (a) afowofa  (b) gbewiri   (d) ojukokuro
    3. Ewo lo ye omo rere?  (a) ole   (b) afowora  (d) itelorun
    4. Eba _______ to nse ojukokoro wi  (a) odo   (b) omode  (d) arugbo
    5. Kini itumo agbewiri.  (a) ole  (b) ole  (d) ika

FIRST TERM EXAMINATION 2022/2023

CLASS: PRIMARY 5                        SUBJECT: YORUBA

   

NAME:………………………………………………………………………………

  1. ERE IDARAYA 
  1. Eniyan melon lo  nta Ayo olopon.  (a) meji  (b) merin  (d) meta
  2. Omo Ayo me lo ni o ngbe oju opon aypo lapopo.  (a) merinla  (b) mejilelogun (d) mejidinladota
  3.  Apa ____________ ni a nta ayo si   (a) osi(b) otun (d) eyin 
  4. Awon ti o nduro woran nibi ere Ayo ni a npe ni _______ (a) onilaja ayo  (b) oniduro ayo   (d) osefe ayo
  5. Iru awo wo ni awo omo ayo. (a) awoeeru  (b) awo eweko  (d) awo pupa

 

  1. AKANLO EDE :
  1. Kini itumo akanlo ede yii: Epa ko boro mo 

(a) ko si epa mo     (b) ko si atunse mo       (d) epa ko si ninu oro

  1. Kini itumo akanlo ede yii: Edun arinle 

(a) edun ti o nrin ni  ile     (b) edun ti o po ganan     (d) eni ti o ti lowo ri, sugbon ti o pada raago
iii. Kini itumo akanlo ede yii:  Fi aake kori: (a) ki eniyan ko jale lati se nnkan    (b) ki eniyan ko jale    (d) kin eniyan fi aake si ori

  1. Kini itumo akanlo ede yii : te oju aje mole  (a) ya ole  (b) ya ika  (d) ya apa
  2. Kini itumo akanlo ede yii : se aya gbangba. (a) ki a ta aya siwaju  (b) ki adoju ko isoro pelu aiberu ati aifoya  (d) ki aya eniyan le

 

  1. OWE ILE YORUBA:  
  1. Pari owe yii:- Agba kii nwa loja. (a) ki inu o bini  (b) ko maa se lagbalagba (d) kori omo tuntun wo
  2. Pari owe yii:- obe ti bale ile kii nje:  (a)ko dun ni  (b) iyo ja ni  (d) iyale ile kii nse
  3. Pari owe yii:- bi okete badagba: (a) a paje ni  (b) omu omo e nii mu  (d) asalo ni
  4. Pari owe yii:- Bomode ba mowo we.  (a) aba agba jeun  (b) owo e mo ni  (d) ate siwaju si
  5. Pari owe yii:- Ile ti a fi ito mo.  (a) adara sini  (b) ategun a gbe lo  (d) iri ni yoo wo

 

  1. ONKA NI EDE  YOURIBA 
  1. Kiini oruko nonba yii ni ede Yoruba: 55  (a) Arundinlogun  (b) Arundinlogoji  (d) Arundinlogota
  2. Kiini oruko nomba yii ni ede Yoruba:  70   (a) adota  (b) Adorin  (d) Ogorun
  3. Kiini oruko nomba yii ni ede Yoruba: 100 (a) Ogota  (b) Ogorun  (d) Ogoji 
  4. Kiini oruko nomba yii ni ede Yoruba: 85  (a) Arundinladorun  (b) Arundinlogoji  (d) Arundinladota
  5. Kiini oruko nomba yii ni ede Yoruba: 110  (a) Ogorun  (b) Ogota  (d)  Adofa

 

 

FIRST TERM EXAMINATION 2022/2023

CLASS: PRIMARY 6                        SUBJECT: YORUBA

   

NAME:………………………………………………………………………………

  1. IWE KIKA: IYI ISE SISE 
  1. Ibo ni orisun gbogbo iwa ibaje? (a) Ile-eko (b) Inu oko (d) Odede
  2. Ewo ni kii se iwa ibaje ninu awon wonyii (a) ole (b) akikanju (d) imele
  3. Iwa Agbeke di awokose fun awon elegbere nitori _________ 

(a) iro pipa re     (b) iwa awon obi re     (d) iwa omoluabi re

  1. Iya Agbeke fun-un ni _________ ko to bere ile-eko

(a) Aso tuntun        (b) imoran    (d) Ounje to dara

  1. Bawo ni Agbeke se jere iwa re ni ile-eko  

(a) Won na-an legbe   (b) won fun-un nise se    (d) won fun-un ni eko ofe 

 

  1. IWE KIKA: IJAKO LERE 
  1. Kini Ajao fe se nigba ti Alagba Alao pariwo pe, “omo naa niyi”? 

(a) o fe fun won ni ehoro    (b) o fe ba ehoro sare    (d) o fe salo 

  1. Won ko pa tie bo o, “tumo si pe”    

(a) won jaa ni patie        (b) won na-an daadaa        (d) won fi iya je e 

  1. Inu Alagba Alao dun nitori won _____     (a) bu Ajao    (b) na Ajao    (d) ko won jade
  2. ______ ti Alagba Alao lo ni o je ki won ri Ajao    (a) ile-eko    (b) ita    (d) ogba
  3. Oga ile-eko se ileri fun Alagba Alao pe oun yoo ____   
  1. sare pe awon obi       (b) lo si ago olopaa (d) ba gbogbo awon akekoo soro   

 

  1. LITIRESO:  EWI OMOLUABI
  1. Ninu ewi yii, a rii pe, omoluabi maa n _____    (a) siwahu    (b) soyaya (d) se wobia    
  2. Ewi yii ko nipe, omoluabi a maa ______  (a) sepe   (b) woso ti ko mo  (d) jeun ni won-tunwon-si
  3. Omo ti yoo je asa mu tumo si  _____    (a) omo ti yoo je ologbon   (b) oruko re yoo maa je Asamu  (d) yoo sa nnkan mu  
  4. Akewi yii fe ki a je ________    (a) omoluabi    (b) ole    (d) gbewiri
  5. Ewi yii so pe:- “a-la-jewora ni _______    (a) gbewiri (b) ole   (d) wobia   

 

  1. ONKA NI EDE YORUBA
  1. Kiini oruko nonba yii ni ede Yoruba: 110  (a) Adofa (b) Ogorun  (d)  Ogota
  1. Kiini oruko nomba yii ni ede Yoruba:  100 (a) Ogorun  (b) Ogota  (d) Ogoji
  2. Kiini oruko nomba yii ni ede Yoruba: 150 (a)  Ogorin  (b) Ogorun  (d) Adojo
  3. Kiini oruko nomba yii ni ede Yoruba: 90  (a) Adota  (b) Ogoji  (d) Adorun
  4. Kiini oruko nomba yii ni ede Yoruba: 60  (a) Ogoji  (b) Ogbon  (d)  Ogota

 

Spread the word if you find this helpful! Click on any social media icon to share