Onka Yoruba (300 – 500)

OSE KEFA

Eka Ise:- Ede 

Akole ise: onka Yoruba (300-500) 

Onka Yoruba lati oodunrun de Eedegbeta

Figo
300Oodunrun 
305Oodunrun ole-marun-un
310Oodunrun ole-mewa 
315Okooleloodunrun odunarun-un 
320Okooleloodunrun 
325Okooleloodunrun ole-marun-un 
330Okooleloodunrun ole-mewaa
335Ojileloodunrun odin marun-un 
345Ojileloodunrun ole-marun-un
350Ojileloodunrin ole-mewaa 
360 Otaleloodunrin 
365 Otaleloodunrun ole-marun-un 
370Otaleloodunrun ole-mewaa
375Orinleloodunrun odin- marun-un
380Orinle looduunrun
385Orunleloodunrun ole-marun-un
390Orunleloodunrun ole-mewaa
395Irinwo odin- marun-un 
400Irinwo 
405Irinwo ole- marun-un 
410Irinwo ole-mewaa
415Okoolenirinwo odin- marun-un 
420Okoolenirinwo 
425Okoolenirinwo ole marun-un 
430Okooleni rinwo ole-mewaa
435Ojilenirinwo odiin marun-un 
440Ojilenirinwo 
445Ojilenirinwo ole-marun-un 
450Ojilenirinwo ole-mewaa
455Otaleiriinwo odin marun-un 
460Otalenirinwo 
465Otalenirinwo ole-marun-un
470Orinlenirinwo odin-mewaa
475Orinlenirinwo odin-marun-un
480Orinlenirinwo 
485Orinlenirinwo ole-marun-un 
490Edagbeta odin-marun-un
500Eedegbeta 

 

EKA ISE: ASA

AKOLE ISE: Sise Itoju Oyun Ni Ona Abinibi Ati Ode-Oni 

Ipo alailegbe ni Yoruba ka omo bibi si nitori won gbagbo pe lai si omo idile ko le e gboro bee si ni itesiwaju ko le si ni awujo.

 

BI A SE N TOJU ABOYUN NI AYE ATIJO

  1. Dide oyun:- itoju aboyun bere ni kete ti won ba ti fi ye si pe oyun naa ti duro . oko tabi agba obinrin ile yoo mu alaboyun lo odo onisegun agbebi tabi babalawo, onisegun agbebi yii yoo de oyun naa ki o maa ba wale tabi baje titi di akoko ti yoo fi bi omo naa
  2. Sise orisi aseje fun alaboyun:- awon aseje yii lo maa n dena aisan bii, oyi oju, ori fifo, inu rirun, ooru inu abbl ti yoo si mu ki omo naa maa dagba ninu ki o si le gbo daradara 
  3. Wiwe ati mimu awon egbo igi: eyi yoo fun aboyun ati omo inu re lokun .

 

BI A SE N TOJU ABOYUN (ODE-ONI)

NI ode-ni, ni kete ti obinrin ko ba ri nnkan osu re ni yoo ti gba ile iwosan lo lati mo boya oyun ti duro.   Oniruru idanlekoo ni awon eleto ilara nse fun awon aboyun lara idanlekoo naa ni yi:

  1. Lilo si ile- iwosan fun ayewo to peye 
  2. Gbigba abere ajesara lati le daabobo omo inu
  3. Jije awon ouje asaraloore bii, ewa eje, eran, wara abbl
  4. Mimu omi daradara
  5. Jije eso ati ewebe 
  6. Sise ere idaraya ni asiko ti o wo
  7. Sise imototo ara atin ayika

 

EKA ISE: LOTIRESO

AKOLE ISE: KEKA IWE APILEKO TI IJOBA YAN. 

Igbelewon

  • Ka onka lati 300-500
  • Salaye bi a se n se itoju alaboyun laye atijo ati lode-oni

Ise asetilewa: ise sise inu iwe ilewo Yoruba Akayege