Ami Ohun lori Ọrọ Onisilebu Meji, Konsonanti Aramupe, Asa, àti Litireso Yorùbá JSS 1 First Term Lesson Notes Week 3

Yorùbá JSS 1 Ọsẹ Kẹta

Eka Iṣẹ: Ede
Akọ́lé Iṣẹ: Ami Ohun lori Ọrọ Onisilebu Meji, Konsonanti Aramupe, Asa, àti Litireso

Akọ́lé Iṣẹ:

  1. Ami Ohun lori Ọrọ Onisilebu Meji:
    • i. ba – ta (shoe) (dd) – kf – kf
    • ii. E – we (leaf) (rd) – f – kf
    • iii. A – ja (dog) (rm) – f – kf
    • iv. Ba – ba (father) (dm) – kf – kf
    • v. Ti – ti (a name of a person) (mm) – kf – kf
  2. Ami Ohun lori Konsonanti Aramupe:
    • Ninu ede Yorùbá, konsonanti aramupe asesilebu ti a ni ni “N” le jéyọ̀ ninu ọrọ bi eyo silebu kan nitori o le gba ami ohun lori. Àpẹẹrẹ:
      • i. n lo – (mr) – k – kf
      • ii. n sun – (md) – k – kf
      • iii. o – ro – n – bo (drdm) – kf – k – kf
      • iv. ba – n – te (ddm) – kf – k – kf
      • v. ko – n – ko (ddd) – kf – k – kf

EKA ISE: ASA
Akọ́lé Iṣẹ: Awon Ẹya Yorùbá ati Ibi ti Wọ́n Tedo Si

  1. Ìtàn:
    • Ẹya Yorùbá ni gbogbo ọmọ Kaaro-Oo-Jiire ṣe ara wọn. Bó tilẹ̀ jẹ́ pé wọ́n kò sí ní ojúkan, ṣùgbọ́n wọn jẹ́ ọmọ ìyá ni gbogbo wọn.
    • Onírúurú ẹya ati èdè ni àwọn ọmọ Yorùbá pin sí káàkiri orílẹ̀-èdè Naijiria.
  2. Awon Ẹya Yorùbá ati Ilu ti Wọ́n Tedo Si:
    • OYO: Ibadan, Iwo, Iseyin, Saki, Ogbonoso, Ikoyi-ile, Igbo-ora, Eruwa, Ikeru, Ejigbo
    • IFE: Osogbo, Ile-Ife, Obaluri, Ifetedo, Araromi, Oke-Igbo
    • IJESA: Ilesa, Ibolan, Ipetu-Ijesa, Ijebu, Ijesa, Esa-Oke, Esa-Odo, Imesi-Ile
    • EKITI: Ado, Ikere, Ikole, Okamesi, Otun, Oya, Isan, Omuo, Ifaki
    • ONDO: Akure, Ondo, Owo, Idanre, Ore, Okitipupa, Ikere, Akoko, Isua, Oke-Igbo
    • EGBA: Abeokuta, Sagamu, Ijebu-Ode, Epe, Igbesa, Awori, Egbedo, Ayetoro, Ibora, Iberekodo, Oke-Odon
    • YEWA: Ilaroo, Ayetoro, Imeko, Ifo, Isaya, Igbogila, Ilobi, Ibese
    • IGBOMINA: Ila-Orayan, Omu-Aran, Oke-Ila, Omupo, Ajase-Ipo
    • ILORIN: Ilorin, Oke-Oyi, Iponrin, Afon, Bala, Ogbondoroko
    • EKO: Isale-Eko, Epetedo, Osodi, Ikotun, Egbe, Agege, Ilupeju, Ikeja, Mushin, Ikorodu, Egbeda
    • EGUN: Ajase, Ibereko, Aradagun

EKA ISE: LITIRESO
Akọ́lé Iṣẹ: Awon Ohun Tó Ya Litireso Sọtọ Si Ede Ojoojumo

  1. Ìtàn:
    • Èdè ni ohun tó jade lénu tí ó ní ìtumọ̀ tó sì jẹ́ ami ìyàtọ̀ láàárín ènìyàn àti ẹranko.
    • Èdè ni a n lo láti gbe èrò ọkàn wa kalẹ̀ fún ẹlòmíràn.
    • Àkójọpọ̀ èdè tí ó di ọrọ ìjìnlẹ̀ ni litireso.
    • Èdè ojoojumo jẹ́ ìpèdè ìgbàrà ènìyàn nínú àwùjọ tó ya ènìyàn àti ẹranko sọtọ.
    • Ìjìnlẹ̀ èdè tí ó kún fún ọgbọ́n, ìmọ̀, òye, iriri, asa, ìgbàgbọ́, àti eto àwùjọ ni litireso.

Igbelewon:

  1. Kọ́ ọrọ onisilebu márùn-ún kí o sì fi ami ohun tí ó yẹ sí i.
  2. Ṣọ́ ìyàtọ̀ mẹ́ta tí ó ya litireso sọtọ sí èdè ojoojumo.
  3. Kọ́ ẹya Yorùbá márùn-ún àti ibi tí wọ́n tedo sí.

Ìṣe Ṣíṣe:

  • Kọ́ ọrọ onisilebu marun-ún pẹ̀lú ami ohun tó dángájìà.

Spread the word if you find this helpful! Click on any social media icon to share