AKOTO AWON ORO TI A SUNKI
OSE KEFA
EKA ISE: EDE
AKOLE ISE: AKOTO AWON ORO TI A SUNKI
Akotoni sipeli titun ti awon onimo ede Yoruba fi enu ko le lori ni odun 1974 lati maa lo.
Sipeli atijo Sipelu titun
Olopa Olopaa
Na Naa
Orun Oorun
Ogun Oogun
Anu Aanu
Papa Paapaa
Suru Suusu
Alafia Alaafia
Oloto Oloooto
Dada Daadaa
Eleyi Eleyii
Marun Marun-un
Alanu Alaaanu
Ologbe Oloogbe
Miran Miiran
Are Aare
Akiyesi:- Iye iro faweli ti a ba pe ni a gbodo se akosile re.
EKA ISE: ASA
AKOLE ISE: IWULO EDE YORUBA
- Ede Yoruba ni a n lo lati ba ara wa so asoye
- Ede ni a fin se ipolowo oja
- Ohun ni a fi n korin nibi ayeye bii, igbeyawo, Isinku, Isile abbl
- A tun le lo ede fun oro asiri
- Ede Yoruba ni a n lo lati fi ke ewi ti yoo dun-un gbo leti,
- Ede ni a n lo lati fi koni ni eko ile nipa eewo ati asa ile wa.
EKA ISE: LETIRESO
AKOLE ISE: LITIRESO ALOHUN TO JE MO ESIN
AWON LITIRESO ALOHUN TO JE MO ESIN KAN TABI OMIIRAN NI ILE YORUBA NI WONYI,
i Oya – pipe
ii Esu – pipe
iii Orin – arungba
iv Ijala -sisun
v Sango – pipe
vi Iyere
vii Ese – Ifa
ESA – IFA / ORUNMILA:
- Awon olusi re ni babalowo ati awon aloye ifa .
- Akoko odun ifa tabi nigba ti nnkan ba ru awon olusin re loju ni won n pe e.
Ounje ifa
Adie
Ewure
Eyele
Igbin
Eja
Epo abbl
Eewo ifa/Orunmila
- Jije isu titun saaju odun
igbagbo Yoruba ti o suyo ni
- Ayanmo
- Ebo-riru ati Olodumare.
IJALA:
- O je Orisa Ogun
- Awon Ode, agbe, alagbede ati awon onise irin gbogbo ni olusi ogun.
- Akoko odun ogun ni won maa n sun ijala.
Ounje Ogun.
Aja
Iyan
Obi
Emu
Esun-isu
Akukodie
Eewo Ogun
- Gbigbe ofifo agbe duro
igbagbo Yoruba ti o suyo
igi, aranko, eye.
- Won maa n sun ijala lati fi juba ogun ati lati fi wa oju rere re
SANGO PIPE:
- orisa yii je olufiran
- Awon adosun sango ati oloye re ni olusin re
- Asiko odun sango ni won maa n pe e
- ilu bata ni ilu sango
Ounje Sango.
Orogbo, agbo funfun
Eewo Sango
Siga mimu, Obi, Ewa sese abbl.
Akiyesi: Sango ni o ni ara ati monamona.
ORIN ARUNGBE:
- Awon Oloro ni olu sin re.
- Asiko odun oro ni a n ko orin yii
Ounje oro
Emu
Aja
Eewo Oro
- Obinrin ko gbodo ri oro
- a kii ri ajeku oro
orisa yii je orisa atunluuse
igbelewon :
- Ko iwulo ede Yoruba marun un
- Ko oro atijo marun un ki o si ko akoto irufe oro bee
- Ko litireso ajemo esin marun-un ki o si salaye
Ise asetilewa:se ise sise lori akole yii ninu iwe ilewo Yoruba Akayege