3RD TERM EXAM QUESTIONS PRIMARY 4 YORUBA LANGUAGE
Â
.
THIRD TERM PROMOTIONAL EXAMINATIONÂ
CLASS: PRIMARY 4 SUBJECT: YORUBA LANGUAGE
NAME:……………………………………………………………………………………
AYEWO
- Iru leta wo ni a nko si obi? (a) leta gbefe    (b) leta aigbefe (d) leta onibeji
- Ise Agbe dara ju ise dokita lo je apeere aroko ________ (a) oniroyin    (b) alalaye      (d)alarinjiyan
- Iyr leta wo ni a maa nko si ile ise? (a) leta onibeji   (b) leta aigbefe  (d) leta gbefeÂ
- Omo ilu wo ni iyaafin Efunroye Tinubu je ________ (a) Oyo   (b) Ilorin  (d) EgbaÂ
- Oloye Tinubu je ibatan __________ (a) Akintoye  (b) kosoko  (d) EfunsetanÂ
- Kiini itumo akanlo ede yi: Kawo bo’tan (a) Jija ola  (b) sise ole (d) yi ya ehana
- Pari owe yii: Agba kii nwa loja (a) ko ri omo tuntu wo  (b) ki iru obi ni  (d) ki oju o ti ni
- Pari owe yii: Bi omode ba mo owo we (a) owo e a mo ni  (b) a ba agba jeun  (d) ari ise seÂ
- Kii ni oruko nomba yii ni ede Yoruba 55: (a) arundinlogbon (b) Arundinlogoji (d) ArundinlogotaÂ
- Kii ni oruko nomba yii ni ede Yoruba 70: (a) Ogota (b) Ogoji (d) Adorin
IWE KIKA: BALOGUN IBIKUNLEÂ
- Balogun Ibikunle je omo (a) Ibadan (b) Ogbomoso (d) IjayeÂ
- Ninu awon ogun ti Balogun Ibikunle ja ni ajabegun ni ogun: ______Â
(a) ijaye ati kutuje (b) Ibadan ati Ijaye (d) ogbomoso ati IbadanÂ
- A fi Ibikunle joye Balogun nitori pe o _______
(a) je omo ogbomoso, o si lowo (b) Jagun ajasegun pupo fun Ibadan (d) bimo, o si koleÂ
- Balogun Ibikunle lokan tumo si pe o ________Â
(a) le farada isoro (b) ijegun pupo (d) ni okan ninu ara reÂ
- Akan soso ajanaku ti migbo kiji kiji, tani won nki bee _______ (a) Balogun Ibikunle      (b) Olubadan (d) efunroye Tinubu
________________________________, _________________________________
Â
IWE KIKA: EFUNROYE TINUBUÂ
- Oloye Tinubu je ibatan ___________ (a) Akintoye (b) Kosoko (d) Geso
- Ohun ti o so Iyaafin Tinubu di olowo ni _________ (a) awon egba (b) owo sise (d) Dosunmu Â
- Awon Egba fi Iyaafin Tinubu je oye iyalode nitori _______Â
(a) awon eru re po  (b) o lowo, olooto, o lola   (d) o ran Egba lowoÂ
- Iyato to wa laarin Tinubu ati Efunsetan ni pe, Tinubu __________
(a) ni opolopo eru  (b) feran gbogbo eniyan   (d) je akoni obinrinÂ
- Ise wo ni baba re nse ni igba aye re _______ (a) Agbe (b) owo sise (d) alagbedeÂ
Â
AKANLO EDE
- Kini itumo akanlo ede yii: Te oju aje mole:Â
(a) ya-apa (b) ja-ole (d) salo
- Kini itumo akanlo ede yii: Epa ko boro mo:Â Â Â Â
(a) kosi epa ninu oro (b) ko si atunse mo (d) ija ko si mo Â
- Kini itumo akanlo ede yii: Edun arinle: _____ (a) Edun ti o nrin nileÂ
(b) Eni ti o ti lowo ri, sugbon ti o pada raago  (d) Eni ti o ngbe inu ile  Â
- Kini itumo akanlo ede yii: Eje orun:Â Â
(a) Omo kekere jojolo (b) Eje to o wa ni orun (d) Omo ti o meje
- Kini itumo akanlo ede yii: Kan oju abe niko: (a)Ki afi abe kan eniyan niko         (b) ki a soro pato si ibi ti oro wa (d) Ki a maa kana be daadaa  Â