2nd Term Summative Test Grade 3 Yoruba
IDANWO SAA KEJI.
ISE (SUBJECT): YORUBA
KILAASI: ALAKOOBERE KETA (PRIMARY 3)
1.Ikoko ni ni ede Geesi.(a) spoon (b) fork (d) pot.
2.___________ ni a máa ń fi rori sún a) ikoko (b) abo (d) irori.
3.Eranko ile ni ___________ je
(a) Ewure (b) Ejo (d) Esinsin
4.Ninu onka Yoruba, ___________
ni 15 je.(a) ookan (b) aarundinlogun (d) oogun.
5.Kini an pe “ERANKO ILE” ni ede Geesi (a) wild animal (b) domestic nature ) domestic animal
6 Kin ni a fi n ru eru ? (n) ori (b) oju (d) enu.
7 Oju ni a ni ? (a) meta (b) merin (d)meji
8. Eya ara ni part of the body ni ede Geesi
BẸẸNI / BEEKO
9. ______ni o ni awo funfun ninu eya ara (a) eti (b) ejika (d) eyin
10.___________ ni o ni awo funfun ninu eya ara (a) eti (b) ejika (d) eyin
APA KEJI.
1. ___________
Ni a maa a n fi bu ounje. (ikoko/awo
2) Kin ni “obe” ni ede Geesi ?
3. K in ni orúkọ ajá lédè geesi
(4) Tolot olo ni ede Geesi,
4.So oruko awon aworan wonyii
- ______________________
- ______________________
- ______________________
- ______________________
- ______________________
- ______________________
- ______________________
- ______________________
- ______________________
- ______________________