1st Term Examination YORUBA JSS 2
Edu Delight Tutors
Subuode Gbaga Gasline Ogun State
1st Term Examination
YORUBA
JSS 2
IPIN A
- Ewo ni ki ise litireso alohun? (a) yala (b) rara (d) okoto tita
- Ewi awon eleegun ni (a) iyere (b) iwi (d) sango pipe
- Awon babalawo ni wom n sun (a) iyere (b) iwi (d) rara
- Bolojo je ewi eya (a) Oyo (b) egbado (d) Ondo
- Okan ninu anfaani litierson alohun nip e a fi n (a) sepe (b) jeun (d) danilaraya
- Faweli aranmupe ni (a) I (b) o (d) an
- Faweli roboto ni (a) an (b) e (d) o
- Iro consonanti ni (a) g (b) u (d) e
- Iro consonanti asesilebu ni (a) f (b) n (d) k
- Oro-ise ni o n je ka mo —– ninu gbolohun (a) abo (b) oluwa (d) koko
- O di dandan ki gbolohun ni ——- (a) apejnwe (b) oro-ise (d) oro-eyan
- Ile ti mo ko tobo, je gbolohun (a) onibo (b) ala kanpo (d) abode
- ‘ase jere ni temi’ je apeere gbolohun (a) ayisodi (b) oniroy ni (d) ijehen
- Igbese kin-in-ni ninu asa igbeyawo ni (a) iwadii (b) idana (d) ifojusode
- Agbodegba laarin iyawo afesona ati oko re ni (a) bab oko (b) Alarina (d) iya iyawo
- Orin ti iyawo n ko ki awon ebi re to ba fe lo sile oko ni (a) ekun iyawo (b) ofo (d) iyere
- Igbeyawo ode oni n daru nitori ko si asa —-mo (a) iwadii (b) ipalemo (d) idana
- Igbeyawo soosi ko fi aaye gba okunrin lati fe ju iyawo ——— lo (a) meji (b) meta (d) kan
- Oro ti won koko se fun iyawo lenu ona ile oko re ni (a) bibo bata re (b) wiwon omi sii loju (d) fif omi we lese
- Ojo wo ni Yoruba n pe ni ojo aiku (a) Monday (b) Sunday (d) Wednesday
IPIN B
DAHUN IBEERE META PERE
1. Bawo ni Yoruba se n ki awon osise won yii (a) Babalawo (b) Agbe (d) Onidiri
2. Kin ni gbolohun? (a) daruko eya gbolohun marun-un nipa ise won
3. (a) ko awon eto ati liana igbeyawo sile ni sise n tele (b) kin ni awon ohun marun ti
Yoruba n gba fun idana
4. Tun awon iro wonyi ko ni liana adako fonoloji (a) k (ii) y (iii) s (iv) o (v) E
5. Koruko amutorun wa mewa (10)