YORUBA LANGUAGE PRIMARY 3 FIRST TERM EXAMINATION
FIRST TERM EXAMINATION
CLASS: PRIMARY 3 SUBJECT: YORUBA LANGUAGE
NAME:……………………………………………………………………………………
- Ewi: Ibawi
E dake je je je
Omo ile-eko, e gbohun enu mi
Eje nkorin ara si yin leti
Bee room ile-eko
To nsojika
- Arofo yii nba omo ______ wi (a) omo ile-eko (b) omo ile-ise
- ______ to gbobawi ni dee ni _____ leyin ola (a) Agba buruku (b) Omo giga
- Omo to gbo _____ nii fi ______ sese rin (a) ija, igi (b) ibawi, mo to
- Eko ndi ________ fomo to gbo ibawi (a) iya (b) deko
- Eyin ______ e gboro _________ yewo (a) Omode, agba (b) gende, ikoko
- Huwa Imoore Si Obi Re: Ewi
Adandori kodo
O nwose eye
Eje ka ronu wo
Ka mob aye ti nto
Ka mohun ti nsele nile, loko ati nibi gbogbo
Baba rook olowo
Nitori ati tomo
Idahun
- _________ dori kodo (a) Adan (b) Igun
- O nwose ______________ (a) Eran (b) Eye
- E toju awon _________ (a) odo (b) obi
- Eyin _________ gbogbo (a) Agba (b) Omode
- __________ yii ko to rara (a) Iwa (b) Ogbon
- Itoju Ara
- Ojoojumo ni ________ nfo eyin re (a) Bola (b) Ade
- A we gbogbo ________ re da saka (a) Ara (b) Inu
- Nitori _________ ara (a) Egbo (b) Eeri
- _________ re a mo nini ni gbogbo igba (a) Aso (b) bata
- Year funwa ________ patapata (a) Ika (b) Obun
- Itoju Ile
- Itoju ___________ se Pataki ara (a) Ile (b) Omi
- Bi ayika ile doti __________ nii fa (a) Oorun (b) Aisan
- Ayika mimo a maa seni ni ________ (a) loge (b) lomo
- Ka maa gbegbein laaye rara, nitori ______ arun (a) itankale (b) iseniloore
- ________ o yemo eniyan (a) iya (b) obun