YORUBA LANGUAGE PRIMARY 5 FIRST TERM EXAMINATION
FIRST TERM EXAMINATION
CLASS: PRIMARY 5 SUBJECT: YORUBA LANGUAGE
NAME:……………………………………………………………………………………
- Ere Idaraya: – Ere Ayo
- ________ ni igi gborogidi ti a gbe iho mejila si (a) opon ayo (b) odo
- _________ ni omo ayo (a) ileke (b) eso igi
- Omo ayo _________ ni o ngbe ni oju opon (a) merinlelogun (b) mejidinladota
- Apa __________ ni a nta ayo sin i ile Yoruba (a) otun (b) osi
- Bawo ni a se nki awon ti o ntaayo? (a) Aredu o (b) mo k iota, mo ki ope
- Akanlo Ede
- Ra owo si (a) seka (b) bebe
- Fi aake kori (a) Ko jale (b) Salo
- Reju (a) Jade (b) Sun
- Hawo (a) ni awon (b) di owo
- Fi imu finle (a) toro nnkan (b) se iwadi oro
- Owe Ile Yoruba
Pari awon owe wonyii
- Agbatan ka gbole bi adaso fole ____ (a) a wo ya (b) a paa laro
- Adan dori kodo: ______ (a) o nwose eye (b) o nwose eran
- Bami na omo mi: ______ (a) owo lo ndo n iya e (b) ko de inu olo mo
- Agba kii nwa loja: _________ (a) Kii nnkan baje (b) kori omo tuntun wo
- Maluu ti ko niru: ______ (a) Oluwa nib a le esinsin (b) iya ajee
- Kini Oruko Awon Nomba Wonyii ni ede Yoruba
- 60 = (ogota, ogoji)
- 70 = (adowa, adorin)
- 50 = (adota, ogoji)
- 40 = (ogoji, ogbon)
- 80 = (ogorin, ogorun)