Yoruba First Term Examination Primary 3

FIRST TERM EXAMINATION 2020/2021

CLASS: PRIMARY 3 SUBJECT: YORUBA LANGUAGE

 

NAME:…………………………………………………………………………………

 

EWI: IBAWI

E dake je je je

Omo ile eko, e gbohun enun mi,

E je nkorin ara si yin leti

Bee romo ile eko

 

IBEERE:

1.) Arofo yii nba omo ________________ wi (a) ile-eko (b) ile-ere

2.) __________ to gbo baawi ni deni _________ leyin ola (a) omo, giga (b) aya, lile

3.) Omo to gbo ____________ nii fi __________ sese rin (a) iya, keke (b) ibawi, moto

4.) Eko ndi _______________ fomo to gbo ibawi (a) deko (b) iyan

5.) Ero ____________ gbogbo (a) iwaju nita ni (b) eyin lawujo ni

 

HUWA IMOORE SI OBI RE: FI ORO TI OYE DI ALAFO WONYII

1.) ____________________ dori kodo (a) Adan (b) Eran

2.) O nwose ___________________ (a) Eran (b) Eye

3.) E toju awon __________________ (a) Obi (b) ore

4.) Eyin _________________ gbogbo (a) agba (b) omode

5.) Baba __________________ lowo (a) nrele (b) roko

 

ITOJU ARA

1.) Kin ni Ade nse ni ojoojumo (a) o nfo eyin re (b) o nfo ese re

2.) Bawo ni Aso Ade se maa nri ni gbogbo igba

(a) aso re maa ndoti (b) aso re maa mo nini

3.) Eeri ara a maa fa _________________ (a) aisan (b) arun

4.) Yera funwa ________________ patapata (a) arun (b) obun

5.) Ki ______________ ma si le gbe o de (a) aisan (b) idoti

 

 

 

 

 

ITOJU ILE: FI ORO TI OYE DI ALAFO WONYII

i.) Ayika ile to doti maa nfa ____________ (a) aisan (b) arun

ii.) ________ kii se ore eniyan (a) arun (b) obun

iii.) Ka ma gba __________ laaye (a) egbin (b) arun

iv.) ____________ nii wo aso ___________ (a) ina, onida (b) omi, arun

v.) Arun iwosi tinu _________ la wa (a) arun (b) egbin

 

IWE KIKA: AINA

i.) Ebi npa ___________ (a) Aina (b) Ojo

ii.) Aina to __________ re lo (a) egbon (b) Iya

iii.) O dahun pe, oun fe je ____________ (a) eba (b) iyan

iv.) Iya re gbe _____________ kana (a) eran (b) omi

v.) Aina fi obe _______________ pelu egusi je eba naa (a) efo (b) ila

 

Spread the word if you find this helpful! Click on any social media icon to share