Primary 5 Yoruba First Term Examination

Table of Contents

FIRST TERM EXAMINATION 2020/2021

CLASS: PRIMARY 5 SUBJECT: YORUBA LANGUAGE

 

NAME:…………………………………………………………………………………

 

ERE IDARAYA: ERE AYO

1.) Omo Ayo me lo ni o ngbe ni oju opon (a) merinlelogun (b) mejidinlogbon (d) mejidinladota

2.) Omo Ayo melon lo nwa ninu iho Kankan (a) mefa (b) merin (d) mejo

3.) Apa ____________ ni a nta ayo si (a) otun (b) osi (d) eyin

4.) Eniyan ______________ ni o nta Ayo olopon (a) meji (b) meta (d) merin

5.) Asiko wo ni a nta Ayo ni ile yoruba (a) osan (b) owuro (d) irole

 

ERE AARIN

1.) Awon wo ni a le ba nidi arin tita (a) gende (b) omo wewe (d) obinrin

2.) Kin ni eso arin fi awo jo (a) paanu to dogun-un (b) ayo (d) oronbo

3.) Ona meji ti a le fi ta arin ni _______ (a) ori ila ati inu ape arin

(b) inu opon ayo ati ori ila (d) ori eni arin ati inu iho alatako

4.) Eso wo ni a le lo dipo eso arin (a) osan mimu (b) ayo (d) oronbo wewe

5.) Ibo la ti nse ere arin (a) ori eni (b) ita gbangba (d) ori pakiti

 

AKANLO EDE:

1.) Kini itumo akanlo ede yii: Fi aake kori:

(a) ki eniyan salo (b) ki eniyan ko jale (d) ki eniyan ku

2.) Kini itumo akanlo ede yii: Kan oju abe ni ko

(a) ba eniyan ja (b) so oro pato sibi ti oro wa (d) fi abe kan eniyan lori

 

3.) Kini itumo akanlo ede yii: Fi imu finle

(a) se iwadi oro (b) fi imu si ile (d) fi imu gbo oorun

4.) Kini itumo akanlo ede yii : Fomo yo (a) Fa omo jade (b) Se asyori (d) pa omo ti

5.) Kini itumo akanlo ede yii: Epa ko boro mo

(a) Epa ko si ninu oro (b) Ko si atunse mo (d) Ko si eniyan mo

 

OWE ILE YORUBA:

(i) Pari owe yii:- Agba kii nwa loja ________________________

(a) Kinu o bini (b) Ki o salo (d) Kori omo tuntun wo

(ii) Pari owe yii:- Bi Okete ba dagba ________________

(a) omo omo e nii mo (b) A pajeni (d) A salo ni

 

 

 

(iii) Pari owe yii:- Bami na omo mi _______________

(a) owo lo ndun iya e (b) Iya e rindin ni (d) Ko de inu olomo

(iv) Pari owe yii:- Ile ti a fi ito mo, _____________

(a) Adara si ni (b) Ategun a gbe lo (d) Iri ni yoo wo

(v) Pari owe yii:- Esin iwaju ________________

(a) Ni o gbe ipokiini (b) lo ya raju (d) ni teyin nwo sare

 

ITAN IRIRI ODE KAN

1.) Akikanju ode ni Oderemi nitoripe _____________ (a) o laya, o loogun

(b) o ti se ise ode fun igba pipe (d) ore Odediran ni (e) o nran awon aladugbo lowo

2.) ‘Ewe sunko’ ninu Ayoka yii tumo si __________

(a) ogun ko je mo (b) Esu gbomi mu (d) Odere mi sunko

3.) Eni ti o pa ekun ninu itan yii ni _____________

(a) Ibon (b) Oderemi (d) Odediran (e) Omo-ode akoko

4.) Omo ode yibon lu Odediran nitori pe ___________

(a) o fe pa a tele (b) Ode ni (d) Iberu ni o fi yinbon (e) O gbabode

5.) Odediran ko je ki won sipa ore re nitori pe ____________

(a) kosi owo (b) eewo ni (d) oku ofo ni (e) o fe mo iku to pa ore re