Ere Okoto títa ni ile Yoruba

 

Class: Pry one

Akole:Ere idaraya ni ile yoruba (ere okoto)

Eniyan meji tabi meta le ta okoto lekan naa.
Ori ile didan ni a ti maa nta okota.
Paanu ti a ka,ti idi re ri soso ni a fi nse okoto.
Okoto maa nj roinroin ti a ba nta.
Ti aba ta okoto ti o njo roinroin a maa nde okoto.
Eni ti ko ba de okoto tire ni emeta a gan ni okoto ni eyin owo.
Okoto fi ara jo(cone).

Ise kilaasi

1.Eniyan melo ni o nta okoto (a)meta (b)mewa

2.Ori ibo ni a ti nta okoto (a)ori eni (b)ori ile didan

3.Kini a fi nse okoto (a)paanu (b) ike

  1. Bawo ni okoto se maa nse ti a ba tatan (a)sun patapata (b)jo roinroin
Spread the word if you find this helpful! Click on any social media icon to share

Add a Comment

Your email address will not be published. Required fields are marked *