Akanlo ede
Class: Pry four
Subject: Yoruba Studies
Akole: Akanlo ede
- Se aya gbangba!
Itumo: ki eniyan doju ko isoro lai beru
- Ya apa!
Itumo: ki eniyan ma itoju owo tabi ohun ti a fi owo ra
- Edun arinle!
Itumo: eni ti o ti loeori sugbon ti opa da rago
- Fi aake kori!
Itumo: ki eniyan ko jale lati se nkan
- Fi aga gbaga!
Itumo:dije, ki eniyan koju ara won lati dan agbara won woo
Ise kilaasi
So itumo awon akanlo ede wonyii:
-
Se aya gbangba – ___________________
-
Edu arinle – ___________________
-
Fi aga gbaga – ___________________
-
Ya apa – _____________________
-
Fi aake kori – ______________________