Yoruba

YORUBA LANGUAGE PRIMARY 2

FIRST TERM EXAMINATION  CLASS: PRIMARY 2 SUBJECT: YORUBA LANGUAGE NAME:…………………………………………………………………………………… Orin akomo niwa: – Omo rere Omo rere kii ___________ (a) puro (b) sun Omo rere kii ___________ (a) jo (b) jale Omo rere kii ___________ (a) sole (b) kawe Omo rere kii ___________ (a) sise (b) seke Omo rere kii ___________ (a) seka (b)

YORUBA 1st term Examination Primary 2

  CLASS: BASIC 2 SUBJECT: Yoruba Pin awon oro wonyi si silebu Eleran adesola Omode Koroba Silebu AKAYE Edu Delight Tutors 1st TERM EXAMINATION Jide je omo onipanle ati alaigboran. Kii f’eti sile si ohun ti awon obi re ba n so. Opo igba ni yio kuro nile ti ko si ni lo si ile-iwe.

FIRST TERM EXAMINATION PRIMARY 6 YORUBA LANGUAGE

FIRST TERM EXAMINATION 2020/2021 CLASS: PRIMARY 6 SUBJECT: YORUBA LANGUAGE   NAME:…………………………………………………………………………………   IWE KIKA: IYI ISE SISE: AGBEKE 1.) Ibo ni orisun gbogbo iwa ibaje? (a) Ile-eko (b) Aarin egbe (d) Odede (e) Inu oko 2.) Ewo ni kii se iwa ibaje ninu awon wonyii (a) ole (b) akikanju (d) (e) ojukokoro 3.) Iwa

ERE IDARAYA NI ILE YORUBA

Pry two Akole:ERE IDARAYA NI ILE YORUBA   ERE BOJUBOJU:Ere bojuboju je okan ninu ere idaraya ti awon omode feran lati maa se akoko ti osupa ba tan imole ni won maa gbadun ere naa, idi niyi ti a fi npa ni ere osupa.Awon omode yoo lo pe are won lati ojule si ojule lati

Ọrọ Ati Idà kejì

Akole:asa imototo   Pry two Akole:oro ati idakeji   Fala si eyi ti onse idakeji awon oro wonyii.   ORO. IDAKEJI 1.Baba. (a)iya (b) Egbon 2.Egbon. (a)ore (b) aburo 3.Onile. (a)alejo (b)ara ilu 4.Omode. (a)Egbon (b)agba 5.Dide (a)joko (b)fosoke

Bi ase nki onise owo ati bi won se nda wo lohun

Pry two Akole:Asa ikini ni ile yoruba Orisirisi ona ni awa yoruba ngba ki ara wa ninu asa ikini ati lati mo omo yoruba lawujo.awon ona naa ni awon wonyi:: 1 ikini ni asiko 2 ikini ni igba 3 ikini si ipo ti aba wa tabi ohun tio ba sele sii eniyan 4 ikini ni

Kinni oruko awon nomba wonyii ni ede yoruba:

Date: Friday, 1st May, 2020. Class: Pry two Subject: Yoruba Studies   Akole:onka ni ede Yoruba lati ori ookan de ogun 1-Ookan 2-Eeji 3-Eeta 4-Eerin 5-Aarun 6-Eefa 7-Eeje 8-Eejo 9-Eesan 10-Ewaa 11-Okanla 12-Ejila 13-Etala 14-Erinla 15-Aarundinlogun 16-Eerindinlogun 17-Eetadinlogun 18-Ejidinlogun 19-Okandinlogun 20-Ogun   Review work: Kinni oruko awon nomba wonyii ni ede yoruba:   1: 8-

SECOND TERM EXAMINATION PRIMARY 2 YORUBA LANGUAGE

SECOND TERM EXAMINATION 2020 CLASS: PRIMARY 2 SUBJECT: YORUBA LANGUAGE NAME:…………………………………………………………………………………… ERE IDARAYA: ERE AYO 1.) Eniyan ___________ lo nta ayo olopon (a) meji (a) merin 2.) Omo ayo ________ lo wa ni oju opon Ayo lapapo (a) merindinlogun (b) mejidinladota 3.) Apa ___________ ni a nta ayo si (a) otun (b) osi 4.) Omo