THIRD TERM PROMOTIONAL EXAMINATION CLASS: PRIMARY 1 SUBJECT: YORUBA LANGUAGE NAME:…………………………………………………………… Alo Apamo: Alo o, alo o, ki lo bo somi, ti ko ro to, kiini o (a) okinni (b) irin Alo o, alo o, opa tinrin kanle o kanrun, kiini o (a) igi (b) ojo kilo ba oba jeun, ti ko
THIRD TERM SUBJECT: YORUBA CLASS: KILAASI KINNI Dahun gbogbo awon ibeere wonyi Ori ibo ni a maa n sun si? (a) ori odo (b) ori sitoofu (d) ori beedi Bi mo ba
FIRST TERM EXAMINATION 2021/2022 CLASS: PRIMARY 1 SUBJECT: YORUBA LANGUAGE NAME:………………………………………………………………………………… 1.) LETA EDE YORUBA A ________ D ________ Ę ________ G _________ I _________ J ________ L ________ N _________ Ǫ ________ R ________ Ș 2.) LILO FAWELI EDE YORUBA PELU AWORAN WON: 1.) (a) awo (b) igba (4.) (a) imu (b) ojo 2.)
THIRD TERM PROMOTIONAL EXAMINATION 2021 CLASS: PRIMARY 1 SUBJECT: YORUBA LANGUAGE NAME:…………………………………………………………………………………… Imototo Fo ___________ re bi o baji (a) eyin (b) inu Ge _________ re ni asiko ti o ye (a) imu (b) irun Ge _____________ re ti ogun sobolo (a) eekanna (b)
SECOND TERM EXAM BASIC 2 YORUBA Silebu mélo lowa nínú àwọn ọ̀rọ̀ wọn yii ? (1) Ade (a) meji (b) meta (2) Ologbon (b) meji (b) meta (3) ilu (a) meji (b) meta (4) Panla (a) meji (b) meta (5)ila (a) meji (b)meta (6)A gbodo fowo bi a ba fe jeun. Beeni
FIRST TERM EXAMINATION CLASS: PRIMARY 5 SUBJECT: YORUBA LANGUAGE NAME:…………………………………………………………………………………… Ere Idaraya: – Ere Ayo ________ ni igi gborogidi ti a gbe iho mejila si (a) opon ayo (b) odo _________ ni omo ayo (a) ileke (b) eso igi Omo ayo _________ ni o ngbe ni oju opon (a) merinlelogun (b) mejidinladota Apa __________ ni
FIRST TERM EXAMINATION CLASS: PRIMARY 4 SUBJECT: YORUBA LANGUAGE NAME:…………………………………………………………………………………… Iwe Kika: – Asinnu Ole __________ ni oruko oja ilu pokii (a) ikilo (b) ayelu Ohun ti o se akoba fun pokii nip e (a) o nra epa je (b) o ni ore pupo __________ ni o bu pokii pe: Lanboroki, oju re jaa (a)
FIRST TERM EXAMINATION CLASS: PRIMARY 3 SUBJECT: YORUBA LANGUAGE NAME:…………………………………………………………………………………… Ewi: Ibawi E dake je je je Omo ile-eko, e gbohun enu mi Eje nkorin ara si yin leti Bee room ile-eko To nsojika Arofo yii nba omo ______ wi (a) omo ile-eko (b) omo ile-ise ______ to gbobawi ni dee ni _____ leyin ola
FIRST TERM EXAMINATION CLASS: PRIMARY 1 SUBJECT: YORUBA LANGUAGE NAME:…………………………………………………………………………………… Iro Ede: Di alafo awon leta wonyii A ______ d ______ e ______ g ______ h ______ j ______ l ______ n ______ o ______ r _______ s Kini Oruko awon aworan wonyii (Lodo, opon) (ibon, igi) (irin, okun) (ayan, eye) (igba, irin) Di awon
1st TERM EXAMINATION CLASS: BASIC 2 SUBJECT: Yoruba Pin awon oro wonyi si silebu 1. Eleran 2. adesola 3. Omode 4. Koroba 5. Silebu AKAYE Jide je omo onipanle ati alaigboran.Kii f’eti sile si ohun ti awon obi re ba n so. Opo igba ni yio kuro nile ti ko si ni lo si
Pry one Ose kefa Akole:onka ni ede Yoruba lati ori ookan de ogun 1-Ookan 2-Eeji 3-Eeta 4-Eerin 5-Aarun 6-Eefa 7-Eeje 8-Eejo 9-Eesan 10-Ewaa 11-Okanla 12-Ejila 13-Etala 14-Erinla 15-Aarundinlogun 16-Eerindinlogun 17-Eetadinlogun 18-Ejidinlogun 19-Okandinlogun 20-ogun-un Ise kilaasi Kinni oruko awon nomba yii ni ede yoruba 1.11(a)etala (b)okanla 2.13(a)okanla (b)etala 3.15 (a)arundinlogun (b)arundinlogbon
Class: Pry one Akole:Ere idaraya ni ile yoruba (ere okoto) Eniyan meji tabi meta le ta okoto lekan naa. Ori ile didan ni a ti maa nta okota. Paanu ti a ka,ti idi re ri soso ni a fi nse okoto. Okoto maa nj roinroin ti a ba nta. Ti aba ta okoto ti
Class: Pry one Subject: Yoruba Studies Akole:lilo leta ede yoruba loro A—Aaja B—Bata D—Doje E—Ejo E—-Eye F—-Fila G—-Gele Gb—-Gbaguda H—-Hausa I—-Igi J—-Jagunjagun K—Kiniun L—–Labalaba M—–Maalu N—–Nahudu O—-Ogongo O—-Ogede P—-Pepeye R—-Rakunmi S—-salubata S—-sango T—-Tafatafa U—-Uku UK u W—-Waala Y—-Yanmuyanmu Ise kilaasi A duro fun ___ (a) aja. (b)ologbo B duro fun kinni ____ (a) apo (b)
Àwọn Faweeli àti konsananti tí ó wà nínú Èdè Yorùbá Class: Pry one Subject: Yoruba Studies Akole: FAWELI ATI KONSONANTI EDE YORUBA Faweli yoruba pin si ona meji awon naa nii 1 Airanmupe 2 Aranmupe 1 FAWELI AIRANMUPE: A E E I O O U 2 FAWELI ARANMUPE: AN EN IN ON
Class: Primary 1 Subject: Home Economics Topic: Alufabeti Ede Yoruba (The Letters of the Alphabets in Yoruba) Duration: 45 minutes Term: First Term Week: Week 8 Set Induction: Begin by displaying the Yoruba alphabet on the board and ask students if they know the names of some Yoruba letters. Previous Knowledge: Students should have a