Subject : Yoruba Class : Jss 2 Term : Second Term Week : Week 6 Topic : EDE: Akaye Oloro Geere/Wuuru. ASA: (a) Ipari ogun . (b) Ona ti a le gba dena ogun (d) anfaani ati aleebu. LIT: Kika iwe Apileko ti ijoba yan. WEEK 1 EDE:
Subject : Yoruba Class : Jss 2 Term : Second Term Week : Week 5 Topic : EDE: Aroko Asotan/Oniroyin ( kiko aroko). ASA: Eto Isigun, Ipalemo ogun jija, awon ohun elo ogun jija ati ete ogun jija. LIT: Litireso Alohun to je mo esin ibile- orin oro, sango pipe, esu
Subject : Yoruba Class : Jss 2 Term : Second Term Week : Week 4 Topic : EDE: Aroso Oniroyin/Asotan ( ilana) ASA: Ogun Jija (awon ohun ti o n fa ogun jija ati ohun ti ko ye ko fa ogun jija, awon oloye ogun). LIT: kika iwe ere onise.
Subject : Yoruba Class : Jss 2 Term : Second Term Week : Week 3 Topic : EDE: Aroko Asapejuwe ( kiko aroko alapejuwe). ASA: Asa Iranra eni lowo (owe, aaro, arokodoko, ebese ) LIT: Kika Iwe Apileko: ere onise ti ijoba yan OSE KETA. AROKO ALAPEJUWE AKOONU:
Subject : Yoruba Class : Jss 2 Term : Second Term Week : Week 2 Topic : EDE: Aroso Alapejuwe (ilana bi a se le ko aroko Yoruba ) ASA: Asa Iranra Eni lowo- Ajo, Esusu, Egbe Alafowosowopo LIT: Litireso Alohun to je mo Esin Ibile- Iyere Ifa, Iwi, Ijala Iremoje.
Subject : Yoruba Class : Jss 2 Term : Second Term Week : Week 1 Topic : Ooka Yoruba OSE KIN-IN-NI ONKA YORUBA (301- 500) DEETI…………………… Gege bi a ti a so seyin pe iyato diedie yoo ba onka 20, 40, 60, ati 80 ni kete ti a
ÕSÊ ORÍ ÕRÕ/ ÀKÓÓNÚ ÀMÚŚE IŚË 1. ÀŚÀ: Ìsômôlórúkô ÀKÓÓNÚ IŚË 1. Ìgbàgbö Yorùbá nípa bí orúkô śe śe pàtàkì tó (orúkô ômô ni ìjánu ômô, orúkô a máa ro ômô) orúkô rere. 2. Ètò ìsômôlórúkô b.a lílo ìrèké, oyin, àádùn, abbl (àwôn ohun èlò ìsômôlórúkô). OLÙKÖ 1. Śe àlàyé ìgbàgbö Yorùbá nípa pàtàkì orúkô.
YORUBA LANGUAGE SCHEME OF WORK JSS 1 SAA ETO ISE FUN SAA KIN-IN-NI YORUBA LANGUAGE SCHEME OF WORK JSS 1 SAA ETO ISE FUN SAA KIN-IN-NI Alifabeeti ede Yoruba Itan isedale Yoruba Oriki litireso Ami ohun lori awon faweeli ati oro onisilebu kan Ile-ife saaju dide oduduwa Ami ohun Awon eya Yoruba
*NAME:……………………………………………………………………………………* *IWE KIKA: DAUDA JALE AGBON * 1.) Omo melo ni baba Dauda bi? (a) meji (b) meta (d) okan (e) merin 2.) Kini ise awon omo wonyii (a) agbe (b) ode (d) ademu (e) akekoo 3.) Eranko wo ni a kii je, ti Dauda maa npa (a) Eye (b) Emo (d) Adan (e) Alangba