ISORI GBOLOHUN

SUBJECT: YORUBA

CLASS: SS 3

TERM: FIRST TERM

WEEK: SECOND WEEK 

OSE KEJI

ISORI GBOLOHUN

Oríkì

Ìsorí gbólóhùn pèlú àpẹẹrẹ

Akóónú

Gbólóhùn ni ìpèdè tí ó kún, tí o sí ní ìse tí ó ń jé. Gbólóhùn jé ìsọ tí ó ní ìtumo kíkún. A fún àwon gbólóhùn Yorùbá ní orúkọ gégé bí íse tí won ń se.

Àpẹẹrẹ:

Bólú je èba.

Bàbá kọ ebè làwon.

Adò njúgbọn, a kó l’ebè ni isorí gbólóhùn.

Nibo omo f’ejo pelu owo yi?

Kilere ti mo so ye ti ohun to ba wo nitori akoka ni.

A to ba n’owo wa se.

Kò si gba lati oruko ṣàyé tí a mo le ti ojó sokan, eyiti o so pe yoo ma fi ona isorí gbólóhù

 

Èyà gbólóhùn

Orisiirisii ni awon eya gbolohun ti o wa ninu ede Yoruba.

Gbólóhùn       Eleyo oro-ise

Gbólóhùn       Olopo oro-ise

Gbólóhùn       Ibeere

Gbólóhùn       Ase

Gbólóhùn       Alaye

Gbólóhùn       Akiyesi alatenumo

Gbólóhùn       Kani/Onikani.

Gbólóhùn       lyisodi

Gbólóhùn       Asodoruko

 

Gbólóhùn Eleyo Oro-Ise-: ni gbolohun ti o maa n ni eyo oro ise kan

Apola oro oruko ati apola oro ise ni o maa n wa ninu gbolohun eleyo oro-lse

Apeere

Baba  te eba

Apola oro-oruko            Apola oro-ise

Olu  sun

Mo ra eran

Tisa na titi

 

Apola oro-oruko + Apola oro-ise.

Adekunle   +     lo ile.

 

Gbólóhùn Olopo Oro-Ise-: Eyi ni gbolohun ti o maa n ni ju oro-ise kan lo o le je meji, meta tabi ju bee lo. Iye oro ti o ba wa ninu gbólóhùn yii ni iye gbolohun ti a le ri fayo ninu re. Apeere:

– Omo naa gba ile baba mo tonitoni

– Omo naa gba ile baba

– Ile baba mo tonitoni

– Bolu sare lo ra aso

– Mama lo ra eran wa

 

Gbólóhùn–Ase: ni a maa n lo lati pase.

Apeere: Wa, Jade, Dake, Lo pon omi wa.

Gbólóhùn lbeere-: ni a maa n lo lati se lbeere tabi wadii nnkan ni orisiirisii ona nipa lilo wunren lbeere bii kin ni elo, nibo, tani, meloo, nigba wo.

Ki ni oruko re?

Nibo ni o n lo?

Elo ni o ra iwe yii?

Tola da ?

Se olu ti wa?

 

Gbólóhùn Kani-: ni a fi maa n so wulewule/kulekule bi nnkan se ri ati idi ti o fi ri bee. Apeere

Bi mo ba lowo, maa kole

Kaka ki n jale, maa seru

Bi Bolu ba ro bee yoo jeko

 

Gbólóhùn Akiyesi Alatenumo-: ni a fi n pe akiyesi si apa kan koko inu odidi gbólóhùn. ‘Ni’ ni atoka gbolohun yii . A le se atenumo fun oluwa ,abo tabi oro-ise. Apeere:

Mo ra iwe

Iwe ni mo ra (abo)

Rira ni mo iwe (oro-ise)

Emi ni mo ra iwe (oluwa)

 

Gbolohun Iyisodi-: ni a fi n ko isele. Apeere:

Bolu ko jeun

Baba ko yo

Se o maa lo?

N ko lo.

Bolu ti de?

Ko tii de

 

IWE ITOKASI

Adewoyin S.Y (2006) Imo, Ede, asa ati Litireso Ede Yoruba Copromutt Publishers o.i 211-217

 

IGBELEWON

Kin ni gbolohun?

Salaye eya gbolohun marun-un pelu apeere kookan.

 

ASA ETO OGUN JIJA

asa :- Eto ogun jija

-oriki

  • orisii ogun ati ohun ti o n fa ogun
  • ipalemo
  • -awon omo ogun, olye ogun

 

AKOONU

  • ogun jija:- ni biba ara eni ja nipa lilo awon omo ogun ti o ni ohun ija oloro ti o le pa ni tabi se ni ni ijamba, iru ibara-eni-ja bee maa n waye laarin ilu si ilu ati eya si eya.

Orisii ogun meji ni o wa ogun adaja ati Ogun ajadiju tabi ajakuakata.

Ogun Adaja:- eyi ni isoro nla ti o n koju enikan tabi idale labe ile won, ti ko kan ara ilu, isoro bee le je aisan buruku, iku gbigbona tabi isoro nla.

 

Ogun Ajadiju tabi Ajaku Akata:- eyi le je ogun adugbo si adugbo, ileto si ileto tabi ilu si ilu,

awon ilu miiran a maa parapo lati gbogun ti eya miiran.

 

Ohun to n fa ogun

Ija lori aala ile

Ipinnu lati ko iwosi tabi ireje

Ojukokoro si oro tabi alumoni ile elomiran

Gbigbeja ilu ti a ni ife si

Sisigun lati fi agbara han

Sisigun lati fi wa owo bi oda owo ba fe da ni

 

IPALEMO

Yoruba je eya kan to maa n fi eto ati arogun si ise won, won kii deede sigun lo ba ilu keji, o ni

awon ilana ti won maa n tele. Bi ogun yoo ba bere, won a koko fi to oba leti ati gbogbo awon to

ye ko gbo leyin eyi ni won yoo fi oro naa si waju ifa.

 

-Ifa Dida:- won kii lo soju ogun laidafa, igbagbo won ni pe ifa yoo se alatileyin won.

-Bibo ogun ati esu:- won yoo se rubo si ogun, eni ti won gba pe o ni gbogbo ohun ija fun ogun nikawo ati pe ki esu ma se won.

-Pipolongo Ogun kaakiri Ilu:- ikede yii yoo de odo awon ara ilu ki won le maa mura sile.

 

Awon oloye ogun

Arare Onakakanfo: ni o je olori ogun ile Yoruba.

Balogun: ni oloye ogun ti ipo re ga ju ni ilu kookan ni ile Yoruba, o si tun ni awon asomogbe

Seriki: ni ipo re powole Balogun oun ni alakoso awon odo.

Asiwaju lo tele seriki oun ni o maa n saaju ogun.

Sarumi: ni olori awon to n fi esin ja loju ogun

 

IGBELEWON

Ko oloye ogun merin ki o si salaye ise pataki okookan won.

 

IWE ITOKASI

Adewoyin S.Y (2006) Imo, Ede, asa ati Litireso Ede Yoruba Copromutt Publishers o.i

 

Lit:     ITUPALE ASAYAN IWE TI IJOBA YAN

Awon eda itan ti o ko pa ninu iwe

 

IGBELEWO

  1. Ki ni gbolohun?
  2. Daruko orisii gbolohun marun-un ti o mo, ki o si salaye meta ninu won pelu apeere mejimeji fun ikookan.
  3. Daruko eda itan mefa ti o kopa ninu iwe Adakedajo.

3   Salaye ipa ti meji ko ninu won.

 

APAPO IGBELEWO

  • Kin ni gbolohun?
  • Daruko orisii gbolohun marun-un ti o mo, ki o si salaye meta ninu won pelu apeere mejimeji fun ikookan.
  1. Daruko eda itan mefa ti o kopa ninu iwe………

4   Salaye ipa ti meji ko ninu won.

5   Ko orisii ogun jija ki o si salaye won.

 

ISE SISE

Ko aroko oniroyin kan ti ko din ni eyo oro odunrun.

 

IWE AKATILEWA

Imo, Ede ASA ati Litireso Yoruba SS2 Adewoyin S.Y.O I 113 – 120

Iwe Adakedajo – Iran Kinni ati Ikeji.

 

ISE ASETILEWA

  1. Gbogbo yin e maa bo. je apeere gbolohun (a) Ibeere (b) ase (d) alaye
  2. Ise oni ti pari je. (a) Gbolohun Ibeere (b) Gbolohun ase (d)Gbolohun alaye
  3. Ona _______ni ogun pin si (a) meji (b) meta (d)merin
  4. ______je okan lara ohun ti o n fa ogun ni aye atijo (a) ile (b) aso (d) omo
  5. Iwe Adakedajo je _______ (a) olorogeere (b) ere onise (d) ewi eyo
  6. Oran salaye je _______ (a) itu ipa (b) ogbon ma wa (d) olobi iyawo
  7. Eda ati ase je _______ (a) Ibeere eyonakankan (b)Ase akodudu (d) Alaye ireko
  8. Iwe Adakedajo ni _______ (a) ere onisekan (b) itu ipa (d) irin ako ikogun kanrin
  9. Eda ati ase je _______ (a) Ibeere eyonakankan (b)ase akodudu (d) Alaye ireko
  10. Iwe Adakedajo ni _______ (a) ere onisekan (b) itu ipa (d) irin ako ikogun kanrin

 

APA KEJI

  1. Kin ni gbolohun?
  2. Salaye isori gbolohun marun-un pelu apeere mejimeji fun ikookan.
  3. Kin ni ogun jija?
  4. ona meloo ni ogun pin si?
  5. Daruko ohun merin ti o n fa ogun.
  6. Daruko ohun ase ati ipa ti o kopa ninu iwe…….
  7. 2 Salaye apeere gbolohun bi won le nko.

 

 

Spread the word if you find this helpful! Click on any social media icon to share