ISORI GBOLOHUN
SUBJECT: YORUBA
CLASS: SS 3
TERM: FIRST TERM
WEEK: SECOND WEEK
OSE KEJI
ISORI GBOLOHUN
Oríkì
Ìsorí gbólóhùn pèlú àpẹẹrẹ
Akóónú
Gbólóhùn ni ìpèdè tí ó kún, tí o sí ní ìse tí ó ń jé. Gbólóhùn jé ìsọ tí ó ní ìtumo kíkún. A fún àwon gbólóhùn Yorùbá ní orúkọ gégé bí íse tí won ń se.
Àpẹẹrẹ:
Bólú je èba.
Bàbá kọ ebè làwon.
Adò njúgbọn, a kó l’ebè ni isorí gbólóhùn.
Nibo omo f’ejo pelu owo yi?
Kilere ti mo so ye ti ohun to ba wo nitori akoka ni.
A to ba n’owo wa se.
Kò si gba lati oruko ṣàyé tí a mo le ti ojó sokan, eyiti o so pe yoo ma fi ona isorí gbólóhù
Èyà gbólóhùn
Orisiirisii ni awon eya gbolohun ti o wa ninu ede Yoruba.
Gbólóhùn Eleyo oro-ise
Gbólóhùn Olopo oro-ise
Gbólóhùn Ibeere
Gbólóhùn Ase
Gbólóhùn Alaye
Gbólóhùn Akiyesi alatenumo
Gbólóhùn Kani/Onikani.
Gbólóhùn lyisodi
Gbólóhùn Asodoruko
Gbólóhùn Eleyo Oro-Ise-: ni gbolohun ti o maa n ni eyo oro ise kan
Apola oro oruko ati apola oro ise ni o maa n wa ninu gbolohun eleyo oro-lse
Apeere
Baba te eba
Apola oro-oruko Apola oro-ise
Olu sun
Mo ra eran
Tisa na titi
Apola oro-oruko + Apola oro-ise.
Adekunle + lo ile.
Gbólóhùn Olopo Oro-Ise-: Eyi ni gbolohun ti o maa n ni ju oro-ise kan lo o le je meji, meta tabi ju bee lo. Iye oro ti o ba wa ninu gbólóhùn yii ni iye gbolohun ti a le ri fayo ninu re. Apeere:
– Omo naa gba ile baba mo tonitoni
– Omo naa gba ile baba
– Ile baba mo tonitoni
– Bolu sare lo ra aso
– Mama lo ra eran wa
Gbólóhùn–Ase: ni a maa n lo lati pase.
Apeere: Wa, Jade, Dake, Lo pon omi wa.
Gbólóhùn lbeere-: ni a maa n lo lati se lbeere tabi wadii nnkan ni orisiirisii ona nipa lilo wunren lbeere bii kin ni elo, nibo, tani, meloo, nigba wo.
Ki ni oruko re?
Nibo ni o n lo?
Elo ni o ra iwe yii?
Tola da ?
Se olu ti wa?
Gbólóhùn Kani-: ni a fi maa n so wulewule/kulekule bi nnkan se ri ati idi ti o fi ri bee. Apeere
Bi mo ba lowo, maa kole
Kaka ki n jale, maa seru
Bi Bolu ba ro bee yoo jeko
Gbólóhùn Akiyesi Alatenumo-: ni a fi n pe akiyesi si apa kan koko inu odidi gbólóhùn. ‘Ni’ ni atoka gbolohun yii . A le se atenumo fun oluwa ,abo tabi oro-ise. Apeere:
Mo ra iwe
Iwe ni mo ra (abo)
Rira ni mo iwe (oro-ise)
Emi ni mo ra iwe (oluwa)
Gbolohun Iyisodi-: ni a fi n ko isele. Apeere:
Bolu ko jeun
Baba ko yo
Se o maa lo?
N ko lo.
Bolu ti de?
Ko tii de
IWE ITOKASI
Adewoyin S.Y (2006) Imo, Ede, asa ati Litireso Ede Yoruba Copromutt Publishers o.i 211-217
IGBELEWON
Kin ni gbolohun?
Salaye eya gbolohun marun-un pelu apeere kookan.
ASA ETO OGUN JIJA
asa :- Eto ogun jija
-oriki
- orisii ogun ati ohun ti o n fa ogun
- ipalemo
- -awon omo ogun, olye ogun
AKOONU
- ogun jija:- ni biba ara eni ja nipa lilo awon omo ogun ti o ni ohun ija oloro ti o le pa ni tabi se ni ni ijamba, iru ibara-eni-ja bee maa n waye laarin ilu si ilu ati eya si eya.
Orisii ogun meji ni o wa ogun adaja ati Ogun ajadiju tabi ajakuakata.
Ogun Adaja:- eyi ni isoro nla ti o n koju enikan tabi idale labe ile won, ti ko kan ara ilu, isoro bee le je aisan buruku, iku gbigbona tabi isoro nla.
Ogun Ajadiju tabi Ajaku Akata:- eyi le je ogun adugbo si adugbo, ileto si ileto tabi ilu si ilu,
awon ilu miiran a maa parapo lati gbogun ti eya miiran.
Ohun to n fa ogun
Ija lori aala ile
Ipinnu lati ko iwosi tabi ireje
Ojukokoro si oro tabi alumoni ile elomiran
Gbigbeja ilu ti a ni ife si
Sisigun lati fi agbara han
Sisigun lati fi wa owo bi oda owo ba fe da ni
IPALEMO
Yoruba je eya kan to maa n fi eto ati arogun si ise won, won kii deede sigun lo ba ilu keji, o ni
awon ilana ti won maa n tele. Bi ogun yoo ba bere, won a koko fi to oba leti ati gbogbo awon to
ye ko gbo leyin eyi ni won yoo fi oro naa si waju ifa.
-Ifa Dida:- won kii lo soju ogun laidafa, igbagbo won ni pe ifa yoo se alatileyin won.
-Bibo ogun ati esu:- won yoo se rubo si ogun, eni ti won gba pe o ni gbogbo ohun ija fun ogun nikawo ati pe ki esu ma se won.
-Pipolongo Ogun kaakiri Ilu:- ikede yii yoo de odo awon ara ilu ki won le maa mura sile.
Awon oloye ogun
Arare Onakakanfo: ni o je olori ogun ile Yoruba.
Balogun: ni oloye ogun ti ipo re ga ju ni ilu kookan ni ile Yoruba, o si tun ni awon asomogbe
Seriki: ni ipo re powole Balogun oun ni alakoso awon odo.
Asiwaju lo tele seriki oun ni o maa n saaju ogun.
Sarumi: ni olori awon to n fi esin ja loju ogun
IGBELEWON
Ko oloye ogun merin ki o si salaye ise pataki okookan won.
IWE ITOKASI
Adewoyin S.Y (2006) Imo, Ede, asa ati Litireso Ede Yoruba Copromutt Publishers o.i
Lit: ITUPALE ASAYAN IWE TI IJOBA YAN
Awon eda itan ti o ko pa ninu iwe
IGBELEWO
- Ki ni gbolohun?
- Daruko orisii gbolohun marun-un ti o mo, ki o si salaye meta ninu won pelu apeere mejimeji fun ikookan.
- Daruko eda itan mefa ti o kopa ninu iwe Adakedajo.
3 Salaye ipa ti meji ko ninu won.
APAPO IGBELEWO
- Kin ni gbolohun?
- Daruko orisii gbolohun marun-un ti o mo, ki o si salaye meta ninu won pelu apeere mejimeji fun ikookan.
- Daruko eda itan mefa ti o kopa ninu iwe………
4 Salaye ipa ti meji ko ninu won.
5 Ko orisii ogun jija ki o si salaye won.
ISE SISE
Ko aroko oniroyin kan ti ko din ni eyo oro odunrun.
IWE AKATILEWA
Imo, Ede ASA ati Litireso Yoruba SS2 Adewoyin S.Y.O I 113 – 120
Iwe Adakedajo – Iran Kinni ati Ikeji.
ISE ASETILEWA
- Gbogbo yin e maa bo. je apeere gbolohun (a) Ibeere (b) ase (d) alaye
- Ise oni ti pari je. (a) Gbolohun Ibeere (b) Gbolohun ase (d)Gbolohun alaye
- Ona _______ni ogun pin si (a) meji (b) meta (d)merin
- ______je okan lara ohun ti o n fa ogun ni aye atijo (a) ile (b) aso (d) omo
- Iwe Adakedajo je _______ (a) olorogeere (b) ere onise (d) ewi eyo
- Oran salaye je _______ (a) itu ipa (b) ogbon ma wa (d) olobi iyawo
- Eda ati ase je _______ (a) Ibeere eyonakankan (b)Ase akodudu (d) Alaye ireko
- Iwe Adakedajo ni _______ (a) ere onisekan (b) itu ipa (d) irin ako ikogun kanrin
- Eda ati ase je _______ (a) Ibeere eyonakankan (b)ase akodudu (d) Alaye ireko
- Iwe Adakedajo ni _______ (a) ere onisekan (b) itu ipa (d) irin ako ikogun kanrin
APA KEJI
- Kin ni gbolohun?
- Salaye isori gbolohun marun-un pelu apeere mejimeji fun ikookan.
- Kin ni ogun jija?
- ona meloo ni ogun pin si?
- Daruko ohun merin ti o n fa ogun.
- Daruko ohun ase ati ipa ti o kopa ninu iwe…….
- 2 Salaye apeere gbolohun bi won le nko.