Third Term JSS 1 EXAMS QUESTIONS YORUBA
3RD TERM EXAMINATION YORUBA JSS 1
3rd TERM EXAMINATION
CLASS: J.S.S SUBJECT: YORUBA STUDIES
SECTION A.
1. Bi ero Yoruba______________ ni Olodumare ran lati da aye
a. Obatala b. Sango d. Oduduwa e. Orumila
2. Ile-iwe mi je aroko ___________ a. asariyanjiyan b. asotan d. asapejuwe
3. Igbese akoko ninu kiko aroko ni _______ a. akole b. ikini ibere d. ipari
4. Leta ti ko fi aaye gba ikini ibere ni ___________ a. leta gbefe b. leta aigbefe d. leta si ore
5. Eniyan laso mi tumo si ___________ a. ore mi ni mo fi n bora b. ibora mi niyi d. iyi ati eye mi
6. Faweli melo ni a ni ninu ede Yoruba? A. 5 b. 6 d. 7
7. konsonati melo ni a ni ninu ede Yoruba?
8. Okan lara ounje Ogun ni a. ebo B aja d. amala e. tuwo.
9. 200 ni ___________ ninu ede Yoruba. A. Ogoji b. Ogun d. ogorun
10. Okan lara awon kokoro wonyi ni o ma n fa iba a. esin sin b. efoo d. aayan
11 19 ni onkan Yoruba ni ____________ a. etadinloyan a. ejidinlogun d. ookandinlogun
12. 20+20 ni onka Yoruba ni___________ a. ogun b. agbon d. ogoji
13. Iro Konsonanti ___________ a. d b. a d. u
14. Iro faweli ni _________ a. b b. d d. e
15 ____________ ni ona ti a n gba ko ero inu eni lori ohun kan ranse si elomiiran
a. leta kiko b. alaye d. ise kan
16. ____________ ni o toka isele inu gbolohun a. ise sise b. oro-ise d. apejuwe
17. A ko le fi ami ohun le ori_______ a. u b. e d. s
18. __________ ni ona ti a n gba bu kun ewa eni a. ewa b. oge sise d. ila kika
19. Tani o tunmo Bibeli si ede Yoruba? A. Ajayi Crowther b. Ojulari Oreodenu d. Muhammed Buhari
20. Awon idile onilu ni nje a. Aderibigbe b. Alabede D Ayandele
Dahun ibeere merin, ibeere kinni se dandan
1. Ko leta si egbon re pe owo owo re ti tan, ki o fi owo ranse si o (150 words)
2. Kini leta gbefe ati leta aigbefe
3. Se alaye ona ti a n gba seda oro oruko pelu apeere
4. Ko onka Yoruba lati 20 -60
5. Ko itan isedala omo Yoruba
6. Ko oruko omo ;oduduwa ati awon omo-omo re meje
7. Kinni owe
Ko apeere marun-un ti orisun owe yoruba ti ma n wa