Primary 3 Yoruba First term exams
NAME OF PUPIL……….………………………….……………………………
DATE………………
SUBJECT: YORUBA
CLASS: BASIC THREE
- Kini ale ri ni ile ikawe (a) Iwe, Bata, Igbale (b) Rula, Iwe, Efun (c) Obe, Akara, Tabili
- Daruko ojo yii ni Yoruba; Sunday (a) Aje (b) Aiku (c) Isegun
- Daruko ojo yii ni Yoruba; Monday (a) Aje (b) Ojoru (c) Ojobo
- Daruko ojo yii ni Yoruba; Tuesday (a) Isegun (b) Eti (c) Abameta
- Daruko Osun yii ni Yoruba; March (a) Seere (b) Erele (c) Erena
- Daruko Osun yii ni Yoruba; November (a) Seere (b) Agemo (c) Belu
- Daruko Osun yii ni Yoruba; August (a) Owere (b) Ogun (c) Ope
- Daruko Eso yii ni Yoruba; Orange (a) Agbado (b) Osan (c) Ewuro
- Daruko Eso yii ni Yoruba; Banana (a) Ibepe (b) Ogede (c) Akara
- Daruko Eso yii ni Yoruba; African star Apple (a) Igba (b) Agbalumo (c) Ata
- Daruko Ede geesi Oro yii; Angeli (a) Anabell (b) Angel (c) Joseph
- Iwa rere Leso ———————- (a) Eran (b) Eniyan (c) Ewure
- Good morning (a) E maa wole (b) Eku ojumo (c) Ekabo
- Good Night ————— (a) Odaro (b) Ekasan (c) Ekale
- Goat (a) Aguntan (b) Ewure (c) Malu
APA KEJI
- Daruko awon Alphabeti Yoruba
_______________________________________________________________
- Ko awon Alphabeti geesi ti ko si ninu Alphabeti Yoruba
_____________________________________________________________
- Ko Alphabeti ti won je meji ninu Alphabeti Yoruba
__________________________________________________________
- Daruko awon ohun ti a le ri ninu yara ikawe
___________________________________________________________